‘Ko sohun ti APC ko fi ni i wọle ibo 2023, gbogbo aye lo ri i pe iṣejọba Buhari peregede’

Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Imo, Ọgbẹni Hope Uzodinma, ti ni bi eto idibo gbogbogboo to maa…

Ori ko eeyan mẹrin yọ lọwọ iku ojiji nibi jamba ọkọ n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin O kere tan, eeyan mẹrin ni ori ko yọ lọwọ iku ojiji lagbegbe…

Wọn pa Adebari si yara ẹ, wọn tun ge ọwọ osi ẹ lọ l’Abẹokuta 

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii, lawọn agbebọn kan ya wọ Ojule kẹrin, Opopona…

Tori wahala to ṣẹlẹ nipa awọn akẹkọọ ti mọto pa, ijọba ti ileewe girama Ojodu pa

Faith Adebọla, Eko Ileewe girama Babs Fafunwa Millenium School, ti wọn n pe ni Ojodu Grammar…

Awọn ọrẹ meji fẹẹ ṣoogun owo, ni wọn ba lọọ ge ori oku ti wọn ṣẹṣẹ sin n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ti wọn ti hu oku ti wọn ṣẹṣẹ sin sitẹ oku, ti…

Tori foonu ẹ ti wọn bajẹ lasiko iwọde, ile-ẹjọ ni kijọba san miliọnu meji fun Soworẹ

Faith Adebọla  Ile-ẹjọ giga apapọ kan to fikalẹ siluu Abuja ti paṣẹ pe kileeṣẹ ọtẹlẹmuyẹ apapọ,…

Buhari kẹdun iku awọn ọmọleewe rẹpẹte tọkọ akẹru pa l’Ojodu

Faith Adebọla, Eko Aarẹ ilẹ wa, Muhammadu Buhari, ti kẹdun iku ojiji to pa awọn akẹkọọ…

Awọn afẹmiṣofo da bọọsi elero duro, wọn dana sun ọkọ ati ero ogoji to wa ninu ẹ

Faith Adebọla Awọn janduku agbebọn tile-ẹjọ ṣẹṣẹ polongo wọn ni afẹmiṣofo ti tun gbọna mi-in yọ…

Nitori ti wọn lo ayederu iwe-ẹri, awọn alaṣẹ Kwara Poly le akẹkọọ mẹfa danu 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn alaṣẹ ile-ẹkọ Gbogbonise tipinlẹ Kwara, (Kwara State Polytechnic), ti le awọn ọmọ…

 Adajọ ti ni ki wọn yẹgi fun Ebenezer to pa aburo ẹ l’Ado-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ile-ẹjọ giga to wa l’Ado-Ekiti ti paṣẹ pe ki wọn yẹgi fun ọmọdekunrin…

Bi ẹ ba fẹẹ dupo oṣelu ni 2023, ẹ tete fijọba mi silẹ bayii- Gomina Dapọ Abiọdun

Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ keje, oṣu kejila, ọdun 2021 yii ni Gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ…