Ọwọ ti ba ọrẹ meji ti wọn ṣa ọlọpaa pa nitori maaluu n’Imẹkọ-Afọn

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Kusogba Isreal; ẹni ọdun mejilelọgbọn pẹlu Oye Ṣẹgun; ẹni ogoji ọdun. Awọn mejeeji…

Ọkada ti wọn ji gbe ni Hussaini n gun kiri ni Ṣagamu, Amọtẹkun ti mu un

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ kin-in-ni, oṣu kin-in-ni, ọdun 2022, ni ikọ Amọtẹkun ipinlẹ Ogun nawọ gan…

Iyabọ Oko tun pada ji saye lẹyin wakati mẹta ti wọn kede pe o ti ku

Faith Adebọla Ọpọ awuyewuye lo n lọ lori ipo ti gbajugbaja oṣere tiata ilẹ wa, Abilekọ…

Ijọba Eko lawọn akẹkọọ ati ileewe Dowen ko mọ ohunkohun nipa iku Sylvester

Jọkẹ Amọri Ijọba ipinlẹ Eko ti ni ileewe Dowen College, to wa ni Ikoyi, atawọn akẹkọọ…

Mọsalasi ati ṣọọṣi ni wọn ti n dawo jọ bayii lati doola awọn mẹreerin ti wọn ji gbe lọna Omu-Aran

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn ajinigbe to ji awọn arinrin-ajo mẹrin: Sunday Balogun, iyawo rẹ, Iya Mary,…

Awọn afọbajẹ yan Lekan Balogun gẹgẹ bii Olubadan tuntun

Ọlawale Ajao, Ibadan Nibi ipade ti awọn eeyan yii, pẹlu apapọ igbimọ Olubadan ṣe ni Gbọngan…

Awọn adigunjale kọ lu Kẹmi Afọlabi, wọn gba nnkan ini ẹ, wọn tun ṣa a ladaa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Pẹlu bo ṣe jẹ pe alaafia ko fi bẹẹ to fun Kẹmi Afọlabi…

Fungba akọkọ, ijọba fun awọn oṣiṣẹ to fakọ yọ lẹbun ọkọ ayọkẹlẹ l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ṣe ni olukọ kan lati ileewe L.A Primary School, Adogbe, nijọba ibilẹ Ariwa…

Nitori ireke aadọta Naira, Hausa gun Yoruba lọbẹ n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ṣe ni ibẹrubojo gbilẹ lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọṣẹ yii, ni ọja kan to…

Ẹlẹwọn mẹrin padanu ẹmi wọn lasiko ti wọn fẹẹ sa kuro lọgba ẹwọn n’Ileefẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹlẹwọn mẹrin niroyin fidi rẹ mulẹ pe wọn padanu ẹmi wọn ni ọgba…

Ọwọ ọlọpaa tẹ Sikiru pẹlu ẹya ara eeyan n’Ikorodu, o loun feẹ fi ṣoogun owo ni

Jọkẹ Amọri Ilu Ikorodu ni awọn ọlọpaa ipinlẹ Eko ti mu ọmọkunrin kan ti wọn porukọ…