Olukọ to fara gbọta lasiko tawọn agbebọn fẹ ji tiṣa meji gbe ni Kwara ṣi n gbatọju lọsibitu

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọbọ, Tọsidee, ọṣẹ yii, ni tiṣa kan ti wọn o darukọ fara gbọta…

EFCC mu babalawo meji at’awọn mi-in fẹsun jibiti n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn ayederu oniṣegun ibilẹ meji kan, Toheeb Ajiṣafẹ ati Usman Ogundayọ, pẹlu awọn…

Ẹ ma polongo saa kẹta fun mi, mo n lọ ni 2023- Buhari

Adefunkẹ Adebiyi Ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu karun-un, ọdun 2023, ko ni i le ọjọ kan si i…

Eyi ni bi ICPC ṣe gbẹsẹ le ile to le lọọọdunrun lọwọ oṣiṣẹ ijọba meji l’Abuja

Adefunkẹ Adebiyi Ajọ to n ri si iwa ajẹbanu ati kikowo ilu jẹ, Independent Corrupt Practices…

Eyi ni ọgbọn ti awọn ajinigbe tun n lo lati ji awọn  ọmọọleewe gbe n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Lati le bọ lọwọ ete awọn ajinigbe, ijọba ipinlẹ Ọyọ ti gba awọn…

Ile-ẹjọ ni Oluwoo ko gbọdọ fi ẹnikẹni joye Mufti Agba fun ilẹ Yoruba

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ile-ẹjọ giga kan niluu Oṣogbo ti paṣẹ pe Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba…

Dele Mọmọdu pada sidii oṣelu, o ti dara pọ mọ PDP

Faith Adebọla Gbajugbaju oniroyin ati ondije dupo aarẹ ilẹ wa nigba kan, Oloye Dele Mọmọdu, ti…

 Wọn ti ileewe giga TASUED pa, nitori rogbodiyan awọn akẹkọọ ati ṣọja

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Latari rogbodiyan to ṣẹlẹ laarin awọn akẹkọọ Tai Solarin University of Education, Ijẹbu-Ode, pẹlu…

Iya atọmọ balẹ satimole, nitori iya ọgọta ọdun ti wọn pa l’Ojodu Abiọdun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Mary Ogbeifu, ẹni ọdun marundinlogoji (35), ati ọmọ ẹ, Godwin Ogbeifu; ẹni ọdun…

Iru ki waa leleyii! Iya ọlọmọ mẹta bẹ sodo toyun-toyun, oku ẹ ni wọn gbejade n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọbọ, Tọsidee, ọṣẹ yii, ni iṣẹlẹ kayeefi kan ṣẹlẹ lagbegbe Ogidi, niluu Ilọrin,…

Ifa o fọre fun Secondus o, ile-ẹjọ lawọn o le da apero PDP duro

Faith Adebọla Idajọ, ‘ki lo ti n wo latọjọ yii’ nile ẹjọ ko-tẹ-mi-lọrun kan to fidi…