O ti ṣẹlẹ! Lori ẹsun ikowojẹ, Tinubu gbaṣẹ lọwọ ọkan ninu awọn minisita ẹ

Faith Adebọla Afaimọ ni mama agbalagba arẹwa to jẹ ọkan lara awọn minisita ninu ijọba Aarẹ…

Ọkọ tipa ya bara wọ agbo ile lojiji niluu Isẹyin, o wole onile, o tun ba ṣọọbu jẹ

Ọlawale Ajao, Ibadan Aimọye eeyan lori ko yọ lọwọ iku ojiji niluu Isẹyin lọsan-an ọjọ Aiku,…

O ma ṣe o, Jennifer lọọ wẹ lodo, ni Ọ̀nì ba gbe e mi

Adewale Adeoye Titi di akoko yii lo jẹ pe inu ọfọ nla ati ẹdun ọkan ni ẹbi, ara ati ọrẹ Oloogbe Jennifer Selengo, ẹni ọdun…

Ọmọ ọran, Alkasim fọbẹ gun baba rẹ pa lọdun tuntun

Adewale Adeoye Teṣan ọlọpaa agbegbe Rijiyar-Zaki, nipinlẹ Kano, ni Ọgbẹni Alkasim Ya’u, ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn kan ti wọn fẹsun kan pe o…

Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ si Yinka Ayefẹlẹ

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọjọ kan n bọ ti gbajugbaja olorin Juju nni, Yinka Ayefẹlẹ, yoo dide…

Ikunlẹ abiyamọ o! Eeyan mẹwaa ku, mẹwaa mi-in fara pa ninu ijamba ọkọ n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Beeyan ba jori ahun, ko si ko ma sunkun to ba ri bi…

Wọn ti mu Saheed, inu ibọwọ tawọn to n ja ẹṣẹ maa n lo lo ko egboogi oloro si

Adewale Adeoye Odo awon oṣiṣẹ ajo to n gbogun ti gbigbe tita ati lilo egboogi oloro…

Eedi ree o! Ẹdamisan yinbọn pa Jeremiah n’Irele, o ni ẹran ẹtu loun pe e

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Baba ẹni ọgọta ọdun kan, Ẹ̀dámísàn Ọwáìyàn, ni wọn ti wọ lọ sile-ẹjọ…

Mathew yii ko lọrọọ gbọ o, ọjọ kẹta to jade lẹwọn lo tun lọọ jale

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọpọ awọn eeyan to wa nibi ti wọn ti n ṣafihan awọn afurasi…

Awọn obinrin fẹhonu han lọ saafin ọba, ni wọn ba dana sun ile kabiesi

Ọlawale Ajao Inu holahilo lawọn olugbe ilu ti wọn n pe ni Boko, nipinlẹ Plateau, wa…

Awọn agbebọn to ji baba atawọn ọmọ ẹ mẹfa gbe n beere fun ọgọta miliọnu Naira 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Inu wahala ati aibalẹ ọkan ni mọlẹbi kan lagboole Sokoto, Òkèkere, niluu Ilọrin,…