Awọn eeyan ipinlẹ Ọṣun ti n reti ipadabọ ẹgbẹ APC – Oyetọla

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Minisita fun ọrọ igbokegbodo ọkọ ati okoowo lori omi, Alhaji Gboyega Oyetọla, ti…

Eyi lohun tawọn aafaa Ilọrin tun ṣe fun Ta-ni-Ọlọhun

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin L’Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kẹfa, oṣu Keji yii, ni idunu ṣubu layọ fun…

Tanka jona gburugburu, dẹrẹba fara pa, ninu ijamba ina ileepo Bovas, n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Bo tilẹ jẹ pe ko sẹni to ku ninu ijamba ina to ṣẹlẹ…

Faanu inu mọṣalaaṣi lawọn eleyii maa n ji tu, ọwọ ti tẹ wọn

Adewale Adeoye Awọn agba bọ wọn ni ọjọ gbogbo ni t’ole, ọjọ kan ni t’olohun. bẹẹ gan-an lo ri fawọn jaguda ẹlẹni mẹta…

O ma ṣe o, akẹkọọ Fasiti OOU gbẹmi ara rẹ sinu otẹẹli

Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ lọrọ bi Oloogbe Adaeze Doris Jaja, orekelẹwa akẹkọọ ileewe ‘Ọlabisi Ọnabanjọ University’ to…

Usman ṣa ọlọkada ladaa yannayanna, lo ba ji ọkada rẹ gbe sa lọ 

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ipinlẹ Niger ni gende kan torukọ rẹ n jẹ Usman Maniya, ẹni ọdun mejilelogun, to n gbe lagbegbe…

Haa! Baba yii jẹ nnkan eewọ, o ti ha patapata

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Niger, ni baba agbalagba kan, Adamu Danga, ẹni ọdun mejilelọgọta wa, nnkan eewọ ti ko yẹ…

Nitori MC Oluọmọ, awọn ẹgbẹ onimọto Eko kọju ija si Wasiu Ayinde 

Monisọla Saka Ọkan pataki lara awọn ọmọ ẹgbẹ onimọto National, iyẹn National Union of Road Transport…

Ọpẹ o, awọn ẹṣọ alaabo doola ẹmi Olori Oba ti wọn pa, wọn mu afurasi mẹtala 

Wọn ni ẹni ti yoo royin ogun ko ni i ku sogun, ọrọ yii gan-an lo…

Latari ẹsun ole ti wọn fi kan an, Lizzy Anjọrin ṣalaye ara ẹ

LizzyliFaith lizzylAdebọla  Ko jọ pe ohun ti gbajumọ oṣere-binrin onitiata ilẹ wa nni, Elizabeth Anjọrin, tawọn…

Fulani tawọn ọlọpaa mu yii ti jẹwọ: Mo wa ninu awọn to yinbọn pa awọn ọba Ekiti

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Niṣe ni ọpọ awọn ọmọ orileede yii n lu ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti,…