Nitori ọwọngogo ounjẹ, Akeredolu fofin de gbogbo ẹgbẹ oniṣowo nipinlẹ Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade,  Akurẹ Latari bi ọwọngogo ounjẹ ṣe n gbilẹ si i kaakiri ipinlẹ Ondo, Gomina…

 Ẹsọ Amọtẹkun ti ri mẹsan-an gba pada ninu awọn arinrin-ajo ti wọn ji gbe l’Akoko  

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Mẹsan-an ninu awọn arinrin-ajo mejila tawọn agbebọn kan ji gbe lagbegbe Ifira Akoko…

Iwadii bẹrẹ lori awọn mẹta ti wọn yin Stephen lọrun pa, ti wọn tun ji mọto ẹ lọ l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Titi dasiko yii lawọn eeyan ṣi n daro iku gigbona tawọn afurasi adigunjale…

Eedi ree o, nitori ounjẹ, iyawo bẹ ọkọ rẹ lori

Titi dasiko yii lawọn eeyan ṣi n kọ haa lori iku ojiji to pa baba kan,…

Nitori ti iya rẹ ba a wi pe o sun sile ọkunrin, ọmọ ileewe girama binu pokunso

Akẹkọọ ileewe girama Naburereya, lorilẹ-ede Kenya, ni Joan Wekesa, ọmọbinrin ẹni ọdun mọkanlelogun ni. Afi bi…

‘Ọkọ mi ko le tẹna kanlẹ fun mi, iṣẹju meji pere lo maa n lo, mi o fẹ ẹ mọ o’

 Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ẹni ọdun mẹẹẹdọgbọn pere (25) ni Lubabatu Ibrahim, obinrin to ṣi duro deede,…

Awọn aṣofin Eko ti fofin de fifi maaluu jẹko ni gbangba, wọn tun ṣofin lori VAT

Faith Adebọla, Eko Bi’ṣẹ o ba pẹ’ni, ẹnikan ki i pẹ iṣẹ, lawọn aṣofin Eko fi…

Awọn ajinigbe to ji Bukunmi atawọn meji mi-in n beere fun miliọnu meji naira l’Omu-Aran

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ilọrin ni ọdọmọkunrin kan ti orukọ rẹ n jẹ Bukunmi n gbe, ko…

Ẹ fura o, Gumi fẹẹ fi abẹwo to ṣe siluu Igboho ko awọn Fulani darandaran wọlu ni o – Awọn ọmọ Oke-Ogun

Faith Adebọla  Ẹgbẹ AOD, to n ri si idagbasoke agbegbe Oke-Ogun, (Alliance for Oke-Ogun Development) ti…

Awọn ọmọ ẹyin Igboho pe DSS lẹjọ, wọn lawọn yoo gba ọgọrun-un miliọnu owo ifiyajẹni

Adefunkẹ Adebiyi Pẹlu gbogbo afojuri ti wọn la kọja lakata DSS, to si tun jẹ awọn…

Miliọnu meji la maa ta maaluu kan ti wọn ba fofin de ka maa fẹran jẹko ni gbangba- Miyetti Allah 

 Faith Adebọla Ẹgbẹ ọlọsin maaluu, Miyetti Allah Cattle Breeders Association (MACBAN), ti parọwa pe kijọba jawọ…