Nitori irin to ji ko, Yisa dero kootu l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Wọn ti foju afurasi ole kan, Yisa Awesu, han ni kootu Majisreeti Ado-Ekiti, fun…

Kafaya fibinu lu ọmọ ẹ pa l’Ogijo, o ni irinkurin ẹ ti pọ ju

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Aaya loun fẹẹ tun oju ọmọ oun ṣe ni, afigba to kọwọ bọ…

Ọkan ninu awọn ibeji Ajogbajesu olorin ti ku o

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Owurọ kutu ọjọ Ẹti, Furaidee, ọgbọnjọ, oṣu keje, ọdun 2021, ni iku ṣoro…

Ẹ wo Abiọdun ati Adeleke ti wọn ja Kọpa John lole n’Ikẹja

Faith Adebọla, Eko Ẹni ogoji ọdun ni Ọgbẹni Abiọdun Idowu yii, oun ati ọrẹ ẹ, Adeleke…

Ọmọọba ti ọlọpaa kogberegbe yinbọn lu l’Oṣogbo ti ku o

Florence Babaṣọla Ọmọọba Saheed Ọlabomi, ọmọkunrin ti ọlọpaa kogberegbe kan yinbọn lu lagbegbe Islahudeen, niluu Oṣogbo,…

Wọn na baba to fẹẹ ba iyawo ọmọ ẹ lo pọ lẹgba nita gbangba

Ọkunrin ti wọn n na lẹgba yii ki i ṣe ọmọ kekere, agbalagba ẹni ọdun mẹtalelọgọta…

Ẹ wo Adebayọ ti wọn lo lu ale ẹ pa, to tun ba oku ẹ lo pọ

Bo tilẹ jẹ pe ọkunrin yii, Adebayọ Kingsley, n ṣe awọn alaye kan nipa iku to…

Ẹ sọ fun ijọba Buhari ko bọwọ f’ofin o, ko lẹtọọ lati ni ki wọn fi tipatipa gbe Sunday Igboho wa si Naijiria-Lọọya Igboho

Jọkẹ Amọri Bi ki i baa ṣe yiyọ Ọlọrun, ati gbogbo ipa ti awọn majẹ-o-bajẹ ṣa,…

Ọwọ ba Fulani mẹta nibi ti wọn ti n da awọn eeyan lọna niluu Tede

Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun Ọwọ awọn ẹṣọ fijilante ti ba awọn afurasi ọdaran Fulani mẹta kan, Yakubu…

Lucky ran awọn ole si ṣọọbu ọga ẹ l’Agọ-Iwoye, gbogbo wọn ni wọn ko sọwọ ọlọpaa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọwọ awọn ọlọpaa Agọ-Iwoye, nipinlẹ Ogun, ti tẹ ọmọkunrin kan torukọ ẹ n…

Ogundoyin tu gbogbo igbimọ awọn aṣofin ipinlẹ Ọyọ ka

Ọlawale Ajao, Ibadan Olori ileegbimọ aṣofin ipinlẹ Ọyọ, Ọnarebu Debọ Ogundoyin, ti tu gbogbo igbimọ ile…