Wọn ti sinku Hadiza, iyawo Oloogbe Shehu Shagari, ti Korona pa

Faith Adebọla Hajiya Hadiza Shagari, iyawo aarẹ ilẹ wa tẹlẹri, Oloogbe Alaaji Shehu Shagari, ti dagbere…

Mo riran si Saraki, yoo di aarẹ Naijiria lọdun 2023 – Wolii Owolabi 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ojisẹ Ọlọrun kan, Christopher Owolabi, to jẹ olori ijọ Christ Apostolic Church, Ori-Oke…

Ibi ti ileeṣẹ nla kan ko ọja si lawọn eleyii lọọ fọ l’Ado-Odo

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta  Ṣinkun bayii lọwọ tẹ awọn baale ilẹ mẹta yii torukọ wọn n jẹ…

Awọn ọlọdẹ yari l’Ọṣun, wọn lawọn o ba Amọtẹkun ṣiṣẹ papọ mọ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Agbarijọpọ ẹgbẹ awọn ọlọdẹ nipinlẹ Ọṣun, (Hunters Group of Nigeria, Osun State Chapter)…

Maaluu ja wọ ọgba awọn agunbanirọ ni Ṣagamu, lo ba n le wọn kiri

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Yiyan bii ologun tawọn agunbanirọ n ṣe laaarọ Ọjọruu, ọjọ kọkanla, oṣu kẹjọ…

Ijọba apapọ ti fẹẹ da too-geeti pada o, wọn ni ẹni ba tọ títì awọn  yoo sanwo

Faith Adebọla Ohun to ti lọ tun ti pada bọ, pẹlu bijọba apapọ ṣe buwọ lu…

Awọn Ibo fẹẹ darapọ mọ Yoruba lati ṣewọde ijangbara ni Washington

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Awọn ọmọ Yoruba ati Ibo ti wọn wa niluu oyinbo ti n gbaradi…

Nibi ti Ogunwusi ti n faṣọ ọlọpaa jale lọwọ ti tẹ ẹ l’Ẹfon-Alaaye

 Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọkunrin ẹni ọdun mejilelogoji kan, Fẹmi Ogunwusi, ti wa ni galagala ọlọpaa nipinlẹ…

Imaamu jade lọ ko wọle mọ, oku ẹ ni wọn ri lọjọ keji n’ijẹbu-Ode

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ariyanjiyan rẹpẹtẹ lo waye lẹyin iku Imaamu agbegbe Atiba, n’Ijẹbu-Ode, iyẹn Sheikh Muṣafau…

Baba to fipa ba awọn ọmọ bibi inu ẹ mẹta lo pọ ti dero Kirikiri

Faith Adebọla, Eko Ile-ẹjọ Majisreeti to wa n’Ikẹja, nipinlẹ Eko, ti paṣẹ pe ki wọn ṣi…

Ọṣun Oṣogbo: Ẹ jokoo sibi ti ẹ ba wa ki ẹ maa wo ayẹyẹ naa

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Kọmiṣanna fun ọrọ aṣa atibudo iṣẹmbaye nipinlẹ Ọṣun, Dokita Ọbawale Adebisi, ti parọwa…