Ileeṣẹ ologun ṣafihan awọn Boko Haram to le lọọọdunrun ti wọn lawọn sọrẹnda

Faith Adebọla Oriṣiiriṣii akọle lawọn agbebọn atawọn afẹmiṣofo Boko Haram kan ti wọn sọrẹnda fawọn ọmoogun…

O ga o, awon ajinigbe tun ji agbẹ kan gbe l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Lẹyin ọjọ kẹta ti awọn ajinigbe ji odidi mọlẹbi kan gbe l’Ekiti, ti…

Awọn aṣofin Ogun kilọ fun Goriọla Hassan, wọn ni ko yee pera ẹ lọba Imobi-Ijẹbu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ile-igbimọ aṣofin ipinlẹ Ogun ti ranṣẹ ikilọ si Ọgbẹni Goriọla Hassan, ọkunrin onitiata…

Ninu ọgba ileewe ni Jamiu ti fipa ba akẹkọọ lo pọ n’Ilese-Ijẹbu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ẹka ti wọn ti n mojuto akọsilẹ iwe awọn akẹkọọ nileewe ẹkọ nipa…

 Kayeefi! Ọmọ ọdun mẹtala pokunso

Kayeefi gbaa ni iku ọmọdebinrin kan ti wọn pe orukọ ẹ ni Precious Iwezoa ṣi n…

Jiipu Lexus bọginni ni Samuel ati Joshua n gun kiri l’Ekoo, aṣe adigunjale ati ẹlẹgbẹ okunkun ni wọn

Faith Adebọla, Eko Meji ninu awọn adigunjale ti ko jẹ kawọn eeyan sun oorun asundọkan l’Ekoo,…

Nitori ẹsun jibiti ori ẹrọ ayelujara, adajọ sọ akẹkọọ LAUTECH atawọn meji mi-in sẹwọn n’lọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Adajọ Sikiru Oyinloye tile-ẹjọ giga kan n’Ilọrin, nipinlẹ Kwara, ti sọ  Ọmọtọshọ Ọlọrunyọmi…

Ọkan ninu awọn Olori Ọba Aromọlaran jade laye

Florence Babaṣọla Ọkan lara awọn iyawo Ọwa Obokun ti ilẹ Ijeṣa, Ọba Gabriel Adekunle Aromọlaran, Olori…

O ma ṣe o, ijamba ọkọ akẹru paayan mẹrin l’Ọyọọ

Faith Adebọla Ijamba ọkọ akẹru pẹlu ọkọ ayọkẹlẹ takisi kan to waye laaarọ ọjọ Aje, Mọnde,…

Ile-ẹjọ ni ki wọn lọọ fi Chidinma to pa baba alaaanu ẹ lọjọsi sẹwọn fun ọgbọn ọjọ l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko O kere tan, ọgbọn ọjọ, ni Chidinma Ojukwu atawọn afurasi ọdaran ti wọn…

Ile-ẹjọ ni ki ọmọọṣẹ Dapọ Abiọdun to lu jibiti l’Amẹrika ṣi wa lẹwọn di 2022

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Abidemi Rufai, ọkan ninu awọn amugbalẹgbẹẹ Gomina Dapọ Abiọdun tẹlẹ yoo ṣi wa…