Awọn Oloro marun-un dero atimọle n’Idiroko, awọn Musulumi to n kirun ni wọn kọ lu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Iṣẹgun, ọjọ kẹta, oṣu kẹjọ yii, lawọn kan ti wọn n ṣe…

Laureta gun baba alaaanu ẹ pa, o tun gbe mọto ọkunrin naa sa lọ

Njẹ ẹyin gbọ nipa ọmọbinrin kan ti wọn lo gun baba alaaanu ẹ pa laipẹ yii?…

Danjuma to lu iyawo ẹgbọn ẹ pa ti wa lahaamọ

Ko si bi ọmọkunrin kan ti wọn pe orukọ ẹ ni Danjuma Haruna yoo ti ṣe…

Wọn loore lọkunrin to ṣegbeyawo pẹlu obinrin mẹrin lọjọ kan ṣoṣo ṣe fun wọn

Ko ṣẹlẹ ri kan ko si, ohun to ba ti waye ti dohun ti aye ri…

Ẹṣọ alaabo mu awọn Fulani darandaran to ya wọ  Kwara lọna aitọ

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ajọ ẹsọ alaabo, ṣifu difẹnsi, ẹka ti ipinlẹ Kwara, pẹlu ajọṣepọ ọmọ ologun…

Wọn ti ge owo ifẹyinti awọn gomina Eko ku si idaji, awọn aṣofin tun wọgile ile kikọ fun wọn

Faith Adebọla, Eko Ileegbimọ aṣofin Eko ti fontẹ lu u pe kijọba din owo ifẹyinti ti…

Ọwọ tẹ ayederu ọlọpaa meji ti wọn n ṣowo igbo l’Ọwọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ayederu ọlọpaa meji lọwọ awọn sọja bareke Ọwẹna, to wa niluu Akurẹ, tẹ…

Ijọba ti ọja Ibẹrẹkodo pa l’Abẹokuta, nitori apọju ẹgbin

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Nitori apọju idọti ati ẹgbin oriṣiiriṣii to wa ninu ọja  Ibẹrẹkodo, l’Abẹokuta, ijọba ipinlẹ…

EFCC gba awọn agunbanirọ nimọran: Ẹ yẹra fun iwa jibiti, o le ba ọjọ ọla yin jẹ

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ajọ to n gbogun ti iwa jibiti ati ṣise owo ilu mọkumọku, EFCC,…

‘Jibiti ni ofin ọdun 1999, afi ki wọn fagi le e’

Arọwa ti lọ setiigbọ awọn orilẹ-ede nla bii Amẹrika, Britain, France, Russia, Germany atawọn mi-in ti…

Kọnstebu ọlọpaa kan ku lasiko tawọn adigunjale ya wọ ilu Iree

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ṣe ni gbogbo ilu Iree, nijọba ibilẹ Boripẹ, nipinlẹ Ọṣun, n gbona janjan…