Abba Kyari yọju sigbimọ olugbẹjọ l’Abuja, o lọwọ oun ree funfun nẹnẹ

Akinkanju ọlọpaa ti wọn ṣẹṣẹ jawee gbele-ẹ fun lẹnu iṣẹ nni, Abba Kyari, ti yọju si…

Ijọba Dapọ Abiọdun ti ko biliọnu mẹrinlelọgọta owo ijọba ibilẹ gba ibomi-in lọ o  -Ladi Adebutu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Iṣẹgun, ọjọ kẹta, oṣu kẹjọ yii, ondije dupo gomina nipinlẹ Ogun lọdun…

DSS lodi si beeli mẹrin ninu awọn ọmọlẹyin Igboho

Faith Adebọla  Bi gbogbo nnkan ba lọ bo ṣe yẹ, o ṣee ṣe ki wọn fi…

Ile-ẹjọ ti paṣẹ pe DSS ko gbọdọ mu Sunday Igboho,  wọn o si gbọdọ halẹ mọ ọn

Faith Adebọla Ile-ẹjọ giga kan to jokoo niluu Inadan, nipinlẹ Ọyọ l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii ti…

Gomina Sanwoolu ṣabẹwo si Aṣiwaju Tinubu ni London

Faith Adebọla O ti to ọjọ mẹta tawọn kan ti n gbe iroyin naa kiri pe…

Eeyan meje ku n’Ibeṣe, nigba tawọn ọlọkada Hausa ati Yoruba kọju ija sira wọn

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bii ere ni kinni ọhun bẹrẹ n’Ibeṣe, nijọba ibilẹ Yewa, nipinlẹ Ogun, iyẹn…

Baba ọgọta ọdun dero ẹwọn l’Ọyọọ, ọmọọdun mẹrinla lo fipa ba lo pọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori to fipa ba ọmọọdun mẹrinla laṣepọ, ile-ẹjọ ti sọ baba ẹni ọgọta…

Wọn ti mu awọn Fulani ajinigbe to pa Olori-Ọdọ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin bii oṣu kan ti wọn yinbọn pa Olori-Ọdọ lagbegbe Akinyẹle, n’Ibadan, ọwọ…

Awọn ọdọ Ọjagbọọrọ ni Kwara pariwo: Gomina gba wa o, gbogbo ileewe ilu wa lo ti d’alapa

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn ẹgbẹ idagbasoke ọdọ agbegbe Ọjagbọọrọ, nijọba ibilẹ Iwọ Oorun Ilọrin (East), nipinlẹ…

Awọn ajinigbe ji dẹrẹba ati ero ọkọ mẹrin gbe l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Awọn afurasi ajinigbe kan ti ṣakọlu si ọkọ akero bọọsi kan ni opopona…

Mọgaji di alaga ere idaraya ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Aje, Monde, ọṣẹ yii, ni Gomina ipinlẹ Kwara, AbdulRahman AbdulRazaq,  kede Ọgbẹni…