Awọn ti a mu nibi iwọde Yoruba Nation ree o – Ọga ọlọpaa Eko

Ọga ọlọpaa ipinlẹ Eko, Hakeem Odumosu, ṣe afihan awọn eeyan mọkandinlaadọta kan loni-in ọjọ aiku, Sannde,…

Terela ja wọ inu Ọja Bode nIbadan, o paayan pẹtẹ

Ko ti i si ẹni to ti mọ iye awọn eeyan ti mọto ajagbe-ejo onigaasi kan…

Ẹ wo awọn ibeji yii, ale iya wọn ni wọn bimọ fun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Philomena ati Patricia Ukange lawọn obinrin meji to gbe ọmọ dani yii, ibeji…

Sunday Igboho pe awọn DSS lẹjọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori bi wọn ṣe fi tipatipa wọnu ile ẹ loruganjọ, ti wọn si…

Bi wọn ṣe n gbogun ti Sunday Igboho ko le da omi tutu si wa lọkan, Yoruba gbọdọ bọ loko ẹru- Aarẹ ogun Kiriji

.Florence Babaṣọla Aarẹ tuntun fun ẹgbẹ Kiriji nilẹ Yoruba (Kiriji Heritage Defenders), Oloye Alebioṣu Kalaowo, ti…

Awa kọ la yinbọn pa Jumọkẹ, ọmọbinrin to ku lasiko iwọde l’Ọjọta- Ileeṣẹ ọlọpaa

Faith Adebọla, Eko Latari ẹsun ti wọn fi kan wọn pe ibọn ọkan lara awọn oṣiṣẹ…

Ka too dibo la ti mọ pe ‘one chance’ ni Gomina Abdulrazak ta a yan -Lai Muhammed

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Gbogbo awọn to gbọ ọrọ to n ti ẹnu Minisita feto iroyin nilẹ…

Kazeem ti dero ile-ẹjọ o, ọrẹ rẹ lo pa to fẹẹ fi ṣoogun owo ni Kwara

  Musa Ibrahim, Alagunmu Ile-ẹjọ Magistreeti kan niluu Ilọrin, ti fi igbẹjọ Kazeem ati awọn mẹta…

Lẹyin to ti lo ọdun mẹta lẹwọn, kootu tu Malachy silẹ, wọn ni ko jẹbi

 Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ẹsun idigunjale ni awọn kan ka si ọkunrin kan torukọ ẹ n jẹ…

Ọlagunju kun baba rẹ bii ewure, lo ba lọọ ta ẹya ara rẹ fun babalawo ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara ti mu ọmọkunrin kan, Ọlagunju, lagbegbe Kajọla, ni Odo-Ọwa,…

Nitori Sunday Igboho, Kunle Adegbitẹ sọrọ sawọn oṣere ẹgbẹ ẹ

Faith Adebọla, Eko Ọkan-o-jọkan ọrọ iwuri lawọn eeyan fi n gboṣuba lasiko yii fun gbajugbaju ajijagbara…