Stephen Ajagbe, Ilorin Lẹyin tijọba ipinlẹ Kwara paṣẹ lọjọ Ẹti, Furaidee, pe awọn akẹkọọ-binrin to jẹ…
Category: Ìròyìn
Ibadan lawọn Fulani ti jí Emmanuel gbe, ilu lsẹyin ni wọn lọọ ja a si lẹ́yìn ti wọn gbowo nla
Ọlawale Ajao, Ibadan Leyin ọjọ mẹrin tó ti wa nígbèkùn àwọn ẹni ibi, ọmọ àgbẹ̀…
Nitori aabọ owo-osu to n san, ẹgbẹ oṣiṣẹ fẹẹ gbena woju Akeredolu l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹgbẹ oṣiṣẹ ipinlẹ Ondo naa lawọn ti ṣetan ati gbena woju Gomina…
Ṣọja, ọlọpaa ati ọtẹlẹmuyẹ kọju ija si Sunday Igboho lọna Ibadan, wọn fẹẹ mu un tipatipa
Awọn ọlọpaa atawọn ẹṣọ agbofinro bii ogoji la gbọ pe wọn dena de ọkan ninu awọn…
Ijinigbe akẹkọọ Zamfara: Awọn obi fibinu ya bo ileewe, wọn ba dukia ijọba jẹ
Faith Adebọla Latari bawọn agbebọn ṣe ji awọn akẹkọọ-binrin to ju ọọdunrun lọ gbe nileewe ijọba…
Tori bi wọn ṣe n ji awọn akẹkọọ gbe, ẹgbẹ olukọ lawọn maa ti ileewe pa
Faith Adebọla Pẹlu bi iṣẹlẹ jiji awọn ọmọleewe ati olukọ gbe lapa Oke-Ọya…
Wọn ba oku ololufẹ meji ninu yara, wọn ni Sniper ni wọn mu
Ki i ṣe ayẹwo dokita lo fidi ẹ mulẹ pe awọn ololufẹ meji, Emmanuel Oshiotu, ẹni…
Awọn akẹkọọ Musulumi lẹtọọ si lilo hijaabu ni Kwara – Ijọba
Stephen Ajagbe, Ilorin Ọrọ lilo ibori fun awọn akẹkọọ-binrin lawọn ileewe tawọn ajọ ẹlẹsin Kristẹni…
Iyawo fi háámà fọ adajọ lori, o lo n yan ọkọ oun lale
Obinrin adajọ kan torukọ ẹ n jẹ Tamara Chibindi, ko ti i bọ ninu wahala to…
Lati ọdun 2017 ni ọta ibọn ọlọpaa ti wa lara mi – Teslim Ibitoye
Florence Babaṣọla Ọkunrin kan, Teslim Ibitoye, ti rawọ ẹbẹ si igbimọ tijọba ipinlẹ Ọṣun gbe kalẹ…
Awọn nọọsi fun Akeredolu lọjọ mẹta ki wọn too bẹrẹ iyansẹlodi l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lẹyin bii osu kan tawọn dokita ti bẹrẹ iyansẹlodi ọlọjọ gbọọrọ…