‘To ba fi maa di ọdun 2023, ẹgbẹ APC yoo ti run Naijiria womuwomu’

Faith Adebọla Awọn agbaagba ilẹ Hausa ti wọn wa ninu ẹgbẹ Northern Elders Forum (NEF) ti…

Nitori ti wọn fi i sahaamọ lọna aitọ, Olushọla wọ ijọba Kwara lọ sile-ẹjọ

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọruu, Wẹsidee, ọṣẹ yii, ni Olusẹgun Olushọla aka (Sholyment), to maa n ta…

Awọn ọlọkada da wahala silẹ l’Oṣogbo lẹyin ti ọlọpaa yinbọn lu ọkan lara wọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ara o rokun, ara o rọ adiyẹ lọwọlọwọ bayii lawọn agbegbe kan niluu…

Awọn ọmọ ileewe girama lọọ wẹ lodo, lọkan ba ri somi n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọmọ ileewe girama ti Gbagba, n’Ilọrin kan ti wọn o ti i mọ…

Wọn ko ti i gba beeli Igboho, wọn tun da a pada satimọle ni Kutọnu

Fun bii wakati mẹwaa ni awon lọọya fi n ba ara won fa a ni ile…

Awọn ọmọ Naijiria fẹẹ gba orileede wọn pada, emi funra mi ni mo maa ṣaaju ipolongo naa-Pasitọ Bakare

Faith Adebọla, Eko  “Ẹnu mi gbọrọ lati sọ ọ, ko sohun ikọkọ kan ti mo ṣe…

Lati Lalupọn ni Sikiru ati Ọlayẹmi ti lọọ jale l’Ọta tọwọ fi ba wọn

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Iṣẹ aje ni wọn lo n sọmọ nu bii oko, ole jija lo…

Loootọ ni Baba Ijẹṣa fẹẹ fẹ mi, ṣugbọn mi o gba fun un – Princess

Faith Adebọla, Eko Lori ẹjọ ti gbajugbaja alawada oṣere tiata ilẹ wa, Ọlanrewaju James Omiyinka, tawọn…

Ọwọ tẹ Abubakar, Fulani darandaran to fẹẹ ji baba arugbo gbe ni Ṣaki

Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun Ori lo ko baba agbalagba ẹni aadọrin ọdun kan, Alagba Samson Ogundiya, diẹ…

Wọn ti mu Taye ati Isiaka, awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun n’Ijanikin  

Faith Adebọla, Eko  ‘Ọmọ oró’ ni wọn mọ awọn gende meji tẹ ẹ n wo ninu…

Seriki awọn Hausa n’Ibadan ti ku o

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọba awọn Hausa iyẹn Sarikin Huasawa ilu Ibadan Ṣaṣa, Alaaji Ahmed Dahiru Zungeeu,…