Ọkada ni Taofeek ji gbe tọwọ NSCDC fi tẹ ẹ lọjọ ọdun Ileya n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ajọ ẹsọ alaabo ṣifu difẹnsi, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti mu adigunjale kan,…

Wọn ti gbe Sunday Igboho lọ sile-ẹjọ ni Cotonou

Faith Adebọla Iroyin to tẹ ALAROYE lọwọ ni pe wọn ti gbe gbaju-gbaja ajafẹtọọ ọmọniyan to…

Nitori Sunday Igboho, awọn ọmọ Yoruba yoo ṣe iwọde ni London

Olufẹmi Iyanda, London Aago mẹwaa owurọ Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii ni awọn ọmọ Yoruba kaakiri ilẹ…

Sunday Igboho ṣi wa ni Cotonou, awọn agbẹjọro kaakiri orileede ti dide atilẹyin fun un

Awọn agbẹjọro lati orileede Olominira Benin, Naijiria, France ati ilẹ Gẹẹsi lo wa lori ọrọ ọkunrin…

Eeyan mẹwaa ku, ọpọ fara pa, nibi ijamba ọkọ lọjọ ọdun Ileya ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Eeyan mẹwaa ni wọn ṣe kongẹ ọlọjọ wọn nibi ijamba ọkọ to waye…

Bi ijọba Buhari ba ro pe mimu Sunday Igboho yoo dẹruba wa, wọn n ṣere ni-Imaamu Yoruba n’Ilọrin

Faith Adebola Imaamu Yoruba niluu Ilọrin, Sheik Abdulraheem Aduranigba, ti sọ pe ọrọ ijọba Naijiria ti…

Gomina Abdulrazak gbe igbimọ ti yoo yanju aawọ Ọffa ati Ẹrinle kalẹ  

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Aje, Monde, ọṣẹ yii, ni Gomina ipinlẹ Kwara, Abdurahman Abdulrazaq, ṣe ifilọlẹ…

Ijọba apapọ ni lati ṣe pẹlẹpẹlẹ lori ọrọ Sunday Igboho- Ladọja

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori bi ijọba orileede Benin ṣe mu ajijagbara ilẹ Yoruba nni, Oloye Sunday…

Sunday Igboho:  O to asiko fun iran Yoruba lati tun ero wọn pa – Yẹmi Farounbi

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkan lara awọn aṣaaju iran Yoruba, Dokita Yẹmi Farounbi, ti sọ pe pẹlu…

Layaajọ ọdun Ileya, Aṣiwaju Tinubu gbadura fawọn alaṣẹ ilẹ wa

Faith Adebọla Layaajọ ayẹyẹ ọdun Ileya, gomina ipinlẹ Eko tẹlẹ, Aṣiwaju Bọla Hammed Tinubu, ti gbadura…

O ṣee ṣe ki orileede Benin ma yọnda Sunday Igboho fun ijọba Naijiria

Faith Adebọla Olori ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oodua, Ọjọgbọn Banji Akintoye, ti ke si awọn ọmọ Yoruba…