Awọn gomina Yoruba ni ki Naijiria pada sijọba ẹlẹkunjẹkun

Faith Adebọla, Eko Awọn gomina ilẹ Yoruba ti dabaa pe kawọn aṣofin ṣatunṣe si ofin ilẹ…

Iwa tawọn tawọn DSS hu si Sunday Igboho le ṣakoba fun iṣọkan orilẹ-ede Naijiria-Awọn ọba Yoruba

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ajọ awọn lọbalọba ilẹ Yoruba ti koro oju si bi ijọba apapọ ṣe…

Ahmed Musa, agbabọọlu ilẹ wa, fẹyawo keji

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Agbami ifẹ ẹlẹẹkeji ni agbabọọlu ilẹ wa nni, Ahmed Musa, ti n luwẹẹ…

Papa iṣere Ilọrin la ti maa ṣe ayẹyẹ ‘Durbar’ ọdun yii – Ilọrin Emirate 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn igbimọ to n mojuto bi ayẹyẹ Durbar to maa n waye niluu…

Gbogbo Ọjọbọ, Tọsidee, lawọn oṣiṣẹ yoo fi maa wọṣo adirẹ nipinlẹ Ọṣun bayii

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Adegboyega Oyetọla, ti kede pe ṣiṣẹ aṣọ adirẹ lọpọ…

Tori arun Korona to tun n yọju, Sanwo-Olu ni kawọn ileejọsin ati ibi ariya din ero ku

Faith Adebọla, Eko Yoruba bọ, wọn ni ifura loogun agba, ijọba ipinlẹ Eko ni toju tiyẹ…

Awọn ajinigbe yinbọn pa Olori-ọdọ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn ajinigbe tun ṣe bẹbẹ n’Ibadan lọjọ Abamẹta, Satide, pẹlu bi wọn ṣe…

Sound Sultan, olorin taka-sufee, ku lojiji

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Abduganiu Ọlanrewaju Fasasi gan-an lorukọ ẹ, ṣugbọn Sound Sultan lọpọ eeyan mọ ọkunrin…

Eyi ga o, wọn tun ji Emir atawọn eeyan mẹwaa mi-in gbe ni Kaduna

Faith Adebọla Afaimọ ki ipinlẹ Kaduna ma gba oye ipinlẹ ti aabo rẹ mẹhẹ ju lọ…

Ọpẹ o, wọn ti ri awọn agbẹ mẹrin ti wọn ji gbe ni Ikosun-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Awọn ọlọpaa nipinlẹ Ekiti ni Satide, ọjọ Abamẹta, ti kede pe awọn ti…

Bireeki tanka epo feeli, lo ba tẹ awọn ọmọleewe mẹẹẹdogun pa

Faith Adebọla Iran buruku ni iran ọhun, iran ti ko dun un wo rara, tori teeyan…