Awọn ‘Iya ooṣa’ naa jade fun iwọde ‘Yoruba Nation’

Faith Adebọla O da bii pe ki i ṣe awọn ọdọ nikan ni ọrọ orileede Yoruba…

Awọn ọlọpaa ti fọn omi gbigbona si awọn oluwọde lara lati tu wọn ka ni Ọjọta

Faith Adebola Bo tilẹ jẹ pe ileeṣẹ ọlọpaa ti ṣekilọ pe ko gbọdọ si iwọde kankan,…

Irọ nla! Ẹnikẹni ko mu emi ni temi o – Sunday Igboho

Oloye Sunday Adeyẹmọ, Sunday Igboho ti sọrọ lori ahesọ kan to n lọ kaakiri bayi pe…

Ohun ti a ṣe n wa Sunday Igboho niyi o – DSS

Ileeṣẹ amunifọba ti wọn n pe ni DSS ti ṣalaye siwaju si i pe idi ti…

Emi kọ ni mo ni ibọn ti DSS lawọn ba nile mi, oogun ibilẹ ni mo fi n daabo bo ara mi-Sunday Igboho

 Faith Adebọla ‘Emi kọ ni mo ni ibọn ti awọn DSS ni awọn ba nile mi,…

Nitori Sunday Igboho, awọn ọmọ Yoruba ilu oyinbo ṣewọde, wọn ni dandan ni ‘Oodua Nation’

Faith Adebọla Latari bawọn ṣọja atawọn ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ ilẹ wa ṣe lọọ ṣakọlu sile Oloye Sunday…

Ọga ọlọpaa Eko ko le di wa lọwọ lati  ma ṣe iwọde wa-Ilana Yoruba

 Faith Adebọla Ẹgbẹ kan to n ja fun ijangbara awọn ọmọ Yoruba, Ilana Yoruba, ti kọ…

Iyawo ku, ọkọ fara pa, ninu ijamba mọto ni marosẹ Abẹokuta si Ṣagamu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Mọto kankan ko kọ lu wọn, ere ti ọkunrin to wa mọto naa…

Awọn adigunjale pa ọlọpaa kan lasiko ti wọn kọ lu ileefowopamọ ni Ọtun-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti  Ọlọpaa kan ti wọn ko ti i darukọ rẹ lo gba ọrun lọ lojiji ninu…

Ibi to ba wu Sunday Igboho ko sa lọ, awa DSS yoo mu un

Faith Adebọla “Ibi yoowu to ba wu Sunday Igboho ni ko sa lọ o, ṣugbọn ko…

Awọn ọtẹlẹmuyẹ n wa ọga agba Fasiti Ọyẹ Ekiti, wọn lo n gbowo-oṣu lọna meji

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Bii ere ori itage lọrọ ri ni ọjọ Iṣẹgun, Tusidee,  ọsẹ yii, laarin ọga agba…