Ọpẹ o, wọn ti ri akẹkọọ Fasiti Ilọrin ti wọn ji gbe pada, eyi ni bi wọn ṣe ri i

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akẹkọọ Fasiti ilu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, Moyọṣọrẹ Bright, to wa ni ipele kin-in-ni…

L’Ọṣun, wọn yinbọn pa aṣaaju ẹgbẹ oṣelu PDP to wale lati orileede Amẹrika

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkunrin ọmọ ẹgbẹ PDP kan to jẹ olukọ lorileede Amẹrika, Ọgbẹni Richard Idowu,…

Adajọ ko gba ẹbẹ Udom to gun ọrẹ rẹ pa, wọn ju u sẹwọn Kirikiri

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Oyindamọla Ọgala, tile-ẹjọ giga kan to wa niluu Ikeja, nipinlẹ Eko, ni wọn wọ Ọgbẹni Emmanuel Udom, to gun ọrẹ rẹ pa ba. Ẹsun…

Opin aye de, pasitọ atawọn ọmo ijọ rẹ lọọ digunjale, mọto olowo nla ni wọn ji gbe

Adewale Adeoye Ọdọ awọn agbofinro agbegbe kan lorileede South Africa, ni Pasitọ Lincoln Tichaona, ẹni ọdun mọkandinlogun, atawọn ọmọ ijọ rẹ meji, Ọgbẹni Chigwasa Innocent, ẹni ogoji ọdun, ati Ọgbẹni Johannes Matema, ẹni ọdun mejidinlọgbọn wa bayii. Ẹsun…

Nitori ọrọ ti ko to nnkan, ọrẹkunrin yii pa afẹsọna rẹ danu

Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ, ọdọ awọn agbofinro agbegbe Githurai 44, niluu Nairobi, orileede Kenya, ni Ọgbẹni Clinton Mwangi,…

Iyawo mi ti gba nnkan mi-in m’ẹsin, ko ṣetọju emi atawọn ọmọ mọ ninu ile-Bakari

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Doocivir Yawe, tile-ẹjọ kọkọ-kọko kan to wa lagbegbe Nyanya, niluu Abuja, ti i ṣe olu ilu ilẹ wa, lawọn tọkọ-taya…

A ko ni i yi ipinnu wa pada, a ti fofin de lilo ike ijẹun fulẹ-fulẹ ‘take-away’ niluu Eko

Adewale Adeoye Ni bayii, ijọba ipinlẹ Eko ti sọ pe ko si ani-ani kankan nibẹ pe awọn ti fofin de…

Abiru ki leleyii, awọn Fulani darandaran ji ọlọpaa mẹta gbe lọ pẹlu ibọn ọwọ wọn

Adewale Adeoye Ni bayii, gbogbo inu igbo ati ibi gbogbo lawọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Delta ni kawọn ọlọpaa ipinlẹ naa maa…

Lẹyin ti wọn lu u bajẹ: Portable olorin figbe bọnu, ṣe o digba ti mo ba ku kẹ ẹ to gbeja mi ni

Adewale Adeoye Gbajumọ olorin hipọọpu nni, Abeeb Okikiọla, ẹni tawọn eeyan mọ si Portable, ti figbe bọnu nileewosan aladaani kan to ti…

Ọlọpaa ti mu Ọlamide, ọpọlọpọ igbo lawọn ọlọpaa ba lọwọ ẹ ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ileeṣẹ ọlọpaa, ẹka tipinlẹ Kwara, ti mu ọkunrin ẹni ọdun mẹtalelogun kan, Ọlamide…

Wọn pariwo ole le kọmiṣanna ti Ayedatiwa yọ nipo lori l’Akurẹ, eyi lohun to ṣe

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ariwo, ‘ole, ole’ lo gba ẹnu pupọ ninu awọn oṣiṣẹ ileeṣẹ to n…