Igbakeji olori awọn aṣofin Kwara ba ilu Isapa kẹdun ọba Oguntọla to waja

Stephen Ajagbe, Ilorin Igbakeji abẹnugan ile-igbimọ aṣofin Kwara, Ọnarebu Adetiba-Ọlanrewaju Raphael, ti ba gbogbo ẹbi ati…

Ẹgbẹrun marun-un pere ni mo ti ri gba latigba ti mo ti n ba wọn lọ soko ole – Ahmed

Stephen Ajagbe, Ilorin Afurasi ẹni ọdun marundinlọgbọn kan, Mọshood Ahmed, tọwọ ajọ NSCDC nipinlẹ Kwara tẹ…

Ọlọpaa lawọn yoo wadii were ti wọn ba ibọ lọwọ rẹ tawọn kan dana sun l’Abule Ado

Faith Adebọla, Eko Ileeṣẹ ọlọpaa Eko lawọn ti bẹrẹ iwadii lori bi awọn janduku kan ṣe…

Nitori ifọrọwerọ ori redio kan to ṣe, wọn ni ki alaga  APC Ọṣun tẹlẹ lọọ rọọkun nile

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn igbimọ agba ninu ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ Ọṣun, iyẹn Osun APC Elder’s…

Ọkan ninu awọn akẹkọọ to fara pa ninu ijamba mọto tọ ṣẹlẹ l’Oṣogbo ti ku o!

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkan lara awọn akẹkọọ ileewe Ataọja High School, to fara pa ninu ijamba…

Awọn eeyan ilu Ifọn Orolu fẹhonu han, wọn lawọn ara Ilobu tun ti n fa wahala lẹsẹ

Florence Babaṣọla, Osogbo Awọn eeyan ilu Ifọn Orolu, nipinlẹ Ọṣun, fẹhonu han lọjọ Iṣẹgun lori bi…

 Lẹyin osu meji ti wọn yinbọn pa awakọ kan l’Akurẹ, ọwọ ọlọpaa tẹ awọn mẹrin

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọwọ ọlọpaa ti tẹ awọn afurasi mẹrin kan lori bi wọn ṣe yinbọn…

Ọba Akiolu bẹ orileede Gẹẹsi lati ran Naijiria lọwọ lori ipenija eto aabo

Faith Adebọla, Eko Ọba ilu Eko, Riliwan Babatunde Akiolu, ti parọwa si orileede Britain lati ma…

A ko ni ilẹ kankan ta a maa fawọn janduku apaniyan ti wọn n pera wọn ni darandaran-Akeredolu

Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu, ko fọrọ awọn darandaran ṣawada lasiko yii rara, o…

Baba Akintoye kilọ fun Tinubu atawọn ẹmẹwa ẹ: Ẹ ma kọyin sibi t’aye kọju si o

Faith Adebọla Olori ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oduduwa, ẹgbẹ to n ja fun ẹtọ ọmọ Yoruba nile…

Akẹkọọ FUNAAB ti wọn ji gbe ti gba itusilẹ

 Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta  Nathaniel Toyinbo Ọlayinka, akẹkọọ ileewe imọ ọgbin, FUNAAB, ti wọn ji gbe labule Itoko,…