Wọn fa aworan ti wọn fi ki Aregbeṣọla ku oriire ọjọọbi ya l’Oṣogbo

Ko jọ pe wahala ‘iwọ lo ju mi, emi o ju ọ’ to n fojoojumọ waye…

Tirela to kun fun fulawa lawọn eleyii digun gba ni Ṣagamu, Eko lọwọ ti tẹ wọn

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọjọ kẹrindinlogun, oṣu kẹrin, ọdun 2021, lawọn ọkunrin mẹrin yii da tirela kan…

Awọn agbebọn ji iyawo olori ọdọ APC ipinlẹ Ọyọ gbe niṣeju ọkọ ẹ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Kọlukọlu ijinigbe to n ṣẹlẹ lemọlemọ nipinlẹ Ọyọ lẹnu ọjọ mẹta yii ti…

Aṣiri tu, wọn lawọn ọmọ Seriki ti wọn le n’Igangan ni wọn ṣi n da Ibarapa laamu

Olu-Theo Omolohun Oke-Ogun. Olobo kan ti ta awọn agbofinro ati ijọba ipinlẹ Ọyọ pe awọn ẹgbẹ…

Ọlọpaa lu ọga ileewe ati tiṣa to ba ọmọ rẹ wi lalubami l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Titi dasiko yii lawọn eeyan ṣi n sọrọ nipa ọlọpaa kan ti wọn…

 Ẹ fadura ran mi lọwọ, ọmọkunrin kan ṣoṣo ti mo bi lo ku sinu ijamba ẹronpileeni yii-Baba Olufade

Alagba George Olufade, baba ọkan ninu awọn awakọ baaluu to gbina lọjọ Ẹti, iyẹn Oloogbe Alfred…

Miliọnu mẹwaa naira miliiki katọọnu kan ati maltina lawọn ajinigbe gba ki wọn too tu mi silẹ-Yusuf

Ibrahim Alagunmu, Ilorin. Hon. Ọlamilekan Yusuf ti ọpọ eniyan mọ si Iyemọja, ti awọn ajinigbe ji…

O ma ṣe o, tirela Dangote tẹ eeyan mẹta pa l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ẹni ti ko ba le ṣe ọkan akin ko le wo oku awọn…

Afẹsọna ṣọja to ku sinu baaluu ologun to ja ni Kaduna daro ololufẹ ẹ

Faith Adebọla, Eko Bunmi Ọladuntoye, afẹsọna awakọ ofurufu awọn ologun, Taiwo Aṣaniyi, to doloogbe lọjọ Ẹti,…

Tinubu pariwo: Ẹ yee forukọ mi purọ o, mi o ni aayo ninu awọn oludije alaga ijọba ibilẹ

Faith Adebọla, Eko Eekan ninu ẹgbẹ oṣelu APC ati gomina ipinlẹ Eko nigba kan, Aṣiwaju Bọla…

Aarẹ Buhari pe Fati Attahiru, iyawo ọga ṣọja to ku lori foonu

Lọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii, ni Aarẹ Muhammadu Buhari pe iyawo olori ologun ile wa to…