Faruq fẹnu kọ lọdọ awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun, ni wọn ba yinbọn pa a n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Kwara ti ni awọn ṣi n wa awọn ọmọ ẹgbẹ…

Awọn eeyan ẹkun Guusu ko ni i dibo fun Ayedatiwa, nitori ọdun mẹrin pere ni yoo lo nipo to ba wọle- Odimayọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Aṣofin to n ṣoju awọn eeyan ijọba ibilẹ Irele ati Okitipupa, nileegbimọ aṣoju-ṣofin…

Iwaju ita ni ọmọdekunrin yii wa ti wọn fi ji i gbe n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Inu ibanujẹ ati iporuru ọkan ni mọlẹbi ọmọdekunrin kan, Abdulrasheed, ẹni ọdun meji…

 Wọn ti mu Raphael, ọrẹbinrin ẹ lo gun pa

Adewale Adeoye Ọdọ awọn alaṣẹ ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Ozoro, nijọba ibilẹ Isoko North, nipinlẹ Delta, ni gende kan, Ọgbẹni Raphael Egbo, ẹni ogun ọdun, wa. Ẹsun tawọn agbofinro ọhun fi…

Boya lọmọ Naijiria yii yoo pada wale mọ, egboogi oloro ni wọn ka mọ ọn lọwọ ni South Africa

Adewale Adeoye Ninu otẹẹli igbalode kan ti wọn n pe ni Houghton, to wa lagbegbe Johannesburg, lorileede South Africa,…

Emi kọ ni mo ni ọmọ Mohbad o, mo maa gbe awọn to n parọ mọ mi lọ si kootu-Ọba Elegushi

Monisọla Saka Ọba Saheed Ademọla Elegushi, ti i ṣe ọba Ikate Elegushi, nipinlẹ Eko, ti jade…

Awọn afọbajẹ Ibadan fọwọ si Ọlakulẹhin gẹgẹ bii Olubadan tuntun

Ọlawale Ajao, Ibadan Lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kejila, oṣu Kẹrin, ọdun yii, ni gbogbo awuyewuye to…

O tan! Adajọ ju Bobrisky sẹwọn oṣu mẹfa

Ẹwọn oṣu mẹfa lai si anfaani fun owo itanran ni Onidaajọ Abimbọla Awogbọrọ ti ile-ẹjọ giga…

Ọgbọn miliọnu Naira lawọn agbebọn to ji akọroyin Channels gbe n beere fun

Monisọla Saka Awọn agbebọn ti ji Ọgbẹni Joshua Rogers, ti i ṣe oniroyin nileeṣẹ tẹlifiṣan Channels,…

O ga o, akẹkọọ Poli Ado-Ekiti binu gbe majele jẹ nitori to fidi-rẹmi ninu idanwo rẹ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ibẹru ati ijaya lo gba ọkan gbogbo awọn  akẹkọọ ati oluko ile-iwe gbogbonise…

Iji lile ṣọṣẹ ni Kwara, ọpọ araalu di alainile lori

Ọpọlọpọ awọn eeyan ni wọn ti di alainile lori latari iji nla kan to ja lasiko…