Ọpẹ o, ara Kollington Ayinla ti ya, eyi lọrọ to sọ lọsibitu to wa

Adewale Adeoye Gbogbo awọn ti wọn ri fidio kan ti Alaaji Kollington Ayinla, ti gbogbo eeyan…

Ba a ṣe yọ Oluọmọ ko kan gomina, eyi nidi ta a fi yọ ọ – Ṣonẹyẹ

Faith Adebọla Gbogbo eto ọhun fẹrẹ ma ju laarin ka diju ka la a lọ, ti…

Ọwọ ti tẹ ọkan lara awọn agbebọn to yinbọn pa Dokita ni Kwara lọjọsi  

  Ibrahim Alagunmu, Ilọrin   Akolo ileeṣẹ ọlọpaa ẹka tipinlẹ Kwara, ni afurasi kan, Mohammadu Aminu, ẹni…

Ijamba ina ba dukia rẹpẹtẹ jẹ lọja Ilupeju, niluu Ọyọ 

 Ọlawale Ajao, Ibadan  Dukia miliọnu rẹpẹtẹ Naira lo ṣegbe sinu ijamba ina to waye lọja Ajegunlẹ,…

Wọn ti yan igbakeji gomina tuntun l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ   Gomina ipinlẹ Ondo, Ọnarebu Lucky Orimisan Ayedatiwa, ti kede orukọ Dokita Ọlayide Adelami…

Adeleke lo wa nidii iyanṣẹlodi awọn oṣiṣẹ kootu l’Ọṣun -Lawal

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Alaga ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress (APC), nipinlẹ Ọṣun, Sooko Tajudeen Lawal, ti…

Eyi ni bi eto isinku Akeredolu yoo ṣe lọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ẹbi gomina nipinlẹ Ondo tẹlẹ, Oloogbe Rotimi Akeredolu, ti kede ọjọ ti…

Joshua yii fo fẹnsi wọ ileeṣẹ kan loru, ọja olowo nla lo ji ko nibẹ

Faith Adebọla Yooba bọ, wọn ni afọkansi ni ole jija, ko sẹni toorun ki i kun…

Ismail ti rugi oyin, oṣiṣẹ ẹgbẹ ẹ ti wọn jọ n ja lo ku mọ ọn lọwọ

Faith Adebọla Ọkunrin ẹni ọdun mejilelọgbọn yii, James Ismail, ti n geka abamọ jẹ lakolo ọlọpaa…

Daniel yii laya o, lati Ondo lo ti lọọ fi ibọn onike jale n’Ijẹbu

Faith Adebọla Ọjọ ti pẹ ti wọn ni gende-kunrin kan, Daniel Iwalokun ti n han awọn…

Ayedatiwa gba iṣẹ lọwọ awọn kọmiṣanna Akeredolu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina ipinlẹ Ondo, Ọnarebu Lucky Orimisan Ayedatiwa, ti gba iṣẹ lọwọ gbogbo awọn…