Ọbasanjọ ṣabẹwo si Oyetọla, o ni onirẹlẹ ati ọmọluabi tootọ ni

Florence Babaṣọla Aarẹ orileede yii tẹlẹ, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ti ṣapejuwe Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Goyega…

Ipinlẹ Ogun lawọn ọmọ keekeeke yii ti n ṣẹgbẹ okunkun, Eko lọwọ ti ba wọn

Faith Adebọla, Eko Ọmọọdun mẹẹẹdogun pere ni Sunday Dare ati Ayọmide Sanni Babatunde, ọmọọdun mẹrinla ni…

Ileeṣẹ ọlọpaa ti da owo tawọn agbofinro fipa gba lọwọ ọkunrin kan to ṣẹṣẹ de lati Dubai pada

Faith Adebọla, Eko  Ọpẹlọpẹ awọn lọgaa-lọgaa ileeṣẹ ọlọpaa Eko ti wọn tete gbọ siṣẹlẹ ọhun, ti…

Makinde yọ ọga agba Fasiti LAUTECH nipo

Ọlawale Ajao, Ibadan Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde ti yọ Ọjọgbọn Michael Olufisayọ Ologunde kuro…

Funkẹ Akindele ra mọto olowo nla

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ki i ṣe mọto kekere rara, iyẹn jiipu tuntun ti gbajugbaja oṣere tiata…

Ọkunrin yii fun ẹni to ya a lowo lọrun pa, o ni ko ma baa tu aṣiri oun ni 

Ifeanyi Ezinwa lorukọ ọkunrin yii, ẹni ọdun mọkandinlọgbọn (29) ni. Oun lo fun ọmọ kekere to…

Ijọba ṣekilọ: Ọtalerugba (260) ọjọ lojo maa fi rọ gidi l’Ekoo lọdun yii

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko ti kilọ pe kawọn eeyan to n gbe lawọn agbegbe…

‘Olowo aja to ba buuyan jẹ l’Ọṣun yoo foju bale-ẹjọ’

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti ke si gbogbo awọn ti wọn n sin aja…

Wọn ti ri ṣọja atawọn meji mi-in tawọn ajinigbe ji gbe n’Ibadan gba pada

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọpọlọpọ wahala lọsan-an ati aisun loru, awọn agbofinro ti tu ṣọja ti…

 Iya gbe miliọnu mẹta ti wọn fẹẹ fi ṣiṣẹ abẹ fọmọ ẹ sa lọ, lọmọ ọdun mẹta naa ba dagbere faye

Epe rabandẹ lawọn abiyamọ aye n gbe obinrin kan ti wọn n pe ni Iya Ada, ṣe…

Awọn ibeji lu ẹgbọn wọn pa nitori ogun baba wọn

Ẹni to j’ogun ko to ẹni ti ogun gbe ni Yoruba wi, beeyan ba si n…