Funkẹ Akindele ra mọto olowo nla

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ki i ṣe mọto kekere rara, iyẹn jiipu tuntun ti gbajugbaja oṣere tiata…

Ọkunrin yii fun ẹni to ya a lowo lọrun pa, o ni ko ma baa tu aṣiri oun ni 

Ifeanyi Ezinwa lorukọ ọkunrin yii, ẹni ọdun mọkandinlọgbọn (29) ni. Oun lo fun ọmọ kekere to…

Ijọba ṣekilọ: Ọtalerugba (260) ọjọ lojo maa fi rọ gidi l’Ekoo lọdun yii

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko ti kilọ pe kawọn eeyan to n gbe lawọn agbegbe…

‘Olowo aja to ba buuyan jẹ l’Ọṣun yoo foju bale-ẹjọ’

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti ke si gbogbo awọn ti wọn n sin aja…

Wọn ti ri ṣọja atawọn meji mi-in tawọn ajinigbe ji gbe n’Ibadan gba pada

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọpọlọpọ wahala lọsan-an ati aisun loru, awọn agbofinro ti tu ṣọja ti…

 Iya gbe miliọnu mẹta ti wọn fẹẹ fi ṣiṣẹ abẹ fọmọ ẹ sa lọ, lọmọ ọdun mẹta naa ba dagbere faye

Epe rabandẹ lawọn abiyamọ aye n gbe obinrin kan ti wọn n pe ni Iya Ada, ṣe…

Awọn ibeji lu ẹgbọn wọn pa nitori ogun baba wọn

Ẹni to j’ogun ko to ẹni ti ogun gbe ni Yoruba wi, beeyan ba si n…

Imaamu ba iyawo oniyawo lo pọ, lọkọ ba gun un pa

Bo tilẹ jẹ pe Umaru Jubrin to gun baba imaamu kan torukọ ẹ n jẹ Alaaji…

Tori wọn n jẹun lasiko aawẹ, ọlọpaa Sharia rọ awọn mọkanla da satimọle ni Kano

Faith Adebọla Kaakiri awọn agbegbe yipo ilu Kano, lapa Oke-Ọya, lawọn ọlọpaa Sharia ti fi pampẹ…

Ilẹ Hausa ni wọn ti n jẹ anfaani ọpọ nnkan amuṣọrọ to jẹ ti ilẹ Yoruba -Ọọni

Adebiyi Adefunkẹ, Abẹokuta Aarẹ Ọna Kakanfo ilẹ Yoruba, Iba Gani Adams, ti sọ  pe bi ko…

  Ọrẹ marun-un jona ku sinu mọto nigba ti wọn n lọ sibi idana ọrẹ wọn

Ko si bawọn eeyan Bekaji ati Karewa, l’Adamawa, ni Yola, yoo ṣe gbagbe ọjọ Abamẹta, Satide,…