Awọn ọmọlẹyin Arẹgbẹṣọla ati Oyetọla ni wọn n da wahala silẹ laarin wọn-Akere

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Kọmiṣanna feto iroyin nipinlẹ Ọṣun lasiko iṣejọba Ọgbẹni Rauf Arẹgbẹṣọla, Ọnarebu Sunday Akere,…

Akẹkọọ Fasiti Ifẹ meji gbe majele jẹ, ọkan ti ku ninu wọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn alaṣẹ Fasiti Ifẹ ti fidi rẹ mulẹ pe ọkan lara awọn akẹkọọ…

Olufọn ti Ifọn Orolu ti waja!

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Bo tilẹ jẹ pe wọn ko ti i kede fun gbogbo ilu, ALAROYE…

Sadik ati Rasak fibọn gba ẹgbẹrun lọna ọgọfa naira lọwọ onirẹsi ni Sango

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Sadik Hassan ati Kudus Rasak lẹ n wo yii, awọn mejeeji ti wa…

A maa yọ orukọ ẹgbẹ oṣelu ti ibo ablẹle wọn ba mu wahala dani danu ni- INEC

Faith Adebọla Ajọ eleto idibo ilẹ wa, Independent Electoral Commission (INEC), ti kede pe lati asiko…

Akara ti wọn po oogun oloro mọ ni Rhoda ati ọrẹkunrin ẹ n ta fawọn ọmọleewe tọwọ fi tẹ wọn

Faith Adebọla Egboogi olóró kan ti wọn n pe ni Arizona, ti wọn lo maa n…

Nitori to yọ ọga agba ileewe naa nipo, ẹgbẹ oṣiṣẹ LAUTECH binu si Makinde

Ọlawale Ajao, Ibadan Ẹgbẹ awọn olukọ Fasiti nilẹ yii, iyẹn Academic Staff Union of Universities (ASUU),…

Ijọba ti ko awọn akẹkọọ ileewe girama to n fa oogun oloro lọ sibudo awọn ọmọ alaigbọran

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko lawọn ọmọleewe marun-un ti wọn wa ninu fọran fidio kan…

 Igbimọ olugbẹjọ da ẹjọ Jẹgẹdẹ nu, wọn l’Akeredolu lo yege

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Igbimọ to n gbọ awuyewuye to su yọ ninu eto idibo gomina to…

Ọsẹ kan lẹyin to wọle ibo, Aarẹ orileede Chad ti ku o!

Faith Adebọla, Eko Orileede Chad, ọkan ninu awọn orileede alaamulegbe Naijiria ti padanu aarẹ wọn, Ọgbẹni…

Mi o le fi ilu Idọgọ ṣere: Oju ọmọ pọn iya mi, ṣugbọn ibẹ ni Ọlọrun ti da a lohun-Ebenezer Obey

Faith Adebọla Ọkan pataki ninu awọn ilu mọ-ọn-ka olorin ti ko ṣee fọọ rọ sẹyin ni…