Awọn agbebọn ti tun ji tiṣa kan gbe n’Ijẹbu o 

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Ṣe ẹ ranti Gbọlahan Ajibọla? Ọmọ ọdun mẹtala to fẹẹ ṣi geeti funya…

EFCC ti mu gomina Imo tẹlẹ, Rochas Okorocha, ju sakolo wọn

Ajọ to n gbogun ti iwa ajẹbanu ati ṣiṣe owo ilu mọkumọku, EFCC, ti mu gomina…

Mutiu ta ọja miliọnu mẹrin aabọ naira to ji fun Kayọde lowo pọọku, lọlọpaa ba ko awọn mejeeji l’Ọta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ileeṣẹ C-WAY ti wọn n ṣe nnkan mimu loriṣiiriṣii niluu Ọta, nipinlẹ Ogun…

Awọn oṣere tiata ṣedaro ọkan ninu wọn to ku lọjọ keji ọjọọbi ẹ

 Faith Adebọla  Ọkan-o-jọkan ọrọ ibanikẹdun lawọn oṣere atawọn ololufẹ tiata ṣi n kọ nipa gbajumọ oṣere…

Ọpẹ o, wọn ti ri dokita ati nọọsi ti wọn ji gbe n’Imẹkọ gba pada

Adebiyi Adefunkẹ, Abẹokuta   Dokita Ọladunni Ọdẹtọla ati Nọọsi Bamgboṣe tawọn ajinigbe ji l’Ọjọruu Wẹsidee, ọsẹ…

Ija pari: Fayoṣe sọrẹnda fun Ṣeyi Makinde, o laṣaaju oun ni

Pẹlu ohun to ṣẹlẹ nibi eto idibo awọn oloye ẹgbẹ oṣelu PDP nilẹ Yoruba, eyi to…

Ajinigbe mẹta ko sọwọ ọlọpaa ni marosẹ Eko s’Ibadan

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Awọn ọlọpaa ipinlẹ Ogun lo mu awọn ọmọkunrin mẹta yii, Nathaniel Jacob; ẹni…

Lori ọrọ Hijaabu, ijọba Kwara paṣẹ kawọn ileewe ti wahala ti ṣẹlẹ wọle

Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Kwara, Abdulrahman AbdulRasak, ti paṣẹ pe kawọn ọmọleewe lawọn ileewe mẹwaa kan…

Ẹ kilọ fun Matawalle ko yee sọsọkusọ o-Gani Adams

Pẹlu ibinu ni Aarẹ Ọna-kakanfo ilẹ Yoruba, Oloye Gani Adams, fi sọrọ si Gomina ipinlẹ Zamfara,…

Awọn Fulani ni kijọba mu Sunday Igboho, ki wọn si da Seriki pada s’Igangan

Latari lile ti wọn le Seriki Fulani, Alaaji Salihu AbdulKadir, kuro nilu Igangan, nijọba ibilẹ Ariwa…

Ọsẹ to n bọ ni wọn yoo sinku Yinka Odumakin siluu Moro, nipinlẹ Ọṣun

Awọn ẹbi oloogbe, Yinka Odumakin, ti ya ọjọ mẹta, iyẹn ọjọ kejilelogun, kẹtalelogun ati ikẹrinlelogun, oṣu…