Mo fọwọ si i kawọn ẹlẹsin abalaye naa maa mura lọ sileewe nibaamu pẹlu ẹsin wọn -Ẹlẹbuibọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Araba Awo tilẹ Oṣogbo, Oloye Ifayẹmi Ẹlẹbuibọn, ti sọ pe ko si ohun…

 Awọn adigunjale yinbọn pa ọlọdẹ meji nileepo kan l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ọlọdẹ meji ti wọn gba lati maa sọ ileepo nla kan to…

Ọba Oniranike pariwo: Bi ohunkohun ba ṣẹlẹ si mi laburu, Ewusi Makun ni kẹ ẹ mu o

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta O tojọ mẹta ti ọrọ ilẹ ti n fa ariyanjiyan laarin Ọba Adewale Adeniji…

Awọn ajinigbe wọ aṣọ ṣọja wa s’Ọbada-Oko, wọn ji ọmọ ọdun mẹtala gbe

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọkan awọn eeyan ko ti i fi bẹẹ balẹ lasiko yii l’Ọbada-Oko, nipinlẹ…

 Ajao ji jẹnẹretọ, ni wọn ba fẹẹ dana sun un l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Diẹ lo ku ki wọn dana sun ole kan tọwọ tẹ lọsan-an gangan,…

Awọn agbebọn yinbọn lu meji ninu awọn ọlọdẹ to n wa dokita ati nọọsi ti wọn ji gbe n’Imẹkọ

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Igbiyanju lati ri dokita ati nọọsi tawọn agbebọn kan ji gbe l’Ọjọruu to kọja…

Wọn ba ageku ara Iya Ganiya Elekuru ninu ile babalawo n’Ileefẹ

Florence Babaṣọla Kayeefi lọrọ naa ṣi n jẹ fun awọn eeyan agbegbe Irẹmọ, niluu Ileefẹ, pẹlu…

Baale ile pokunso sẹgbẹẹ titi l’Alakia, n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Oku eeyan lawọn oṣiṣẹ ati ara ileeṣẹ Nigerian Brewries, lọna marosẹ Ibadan si…

A fara mọ atunto, kijọba si ṣepade pẹlu awọn janduku, Boko Haram- Awọn agbaagba ilẹ Hausa

Ẹgbẹ awọn agbaagba ilẹ Hausa ti wọn n pe ni Northern Elders Forum atawọn ẹgbẹ bii…

Nibi t’ọba alaye ti n sa fun awọn ajinigbe ni wọn ti yinbọn fun un l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Awọn agbebọn kan tawọn eeyan fura si bii ajinigbe ti yinbọn lu Elewu…

Wọn ti mu Aafaa Jamiu to fẹẹ fọmọ ọdun mẹẹẹdogun  ṣoogun owo ni Sango

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Aafaa Amọdu Jamiu ree, ẹni ọdun mẹtadinlogoji ni. Awọn ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti…