Nitori Korona, gomina Eko sun iwọle awọn oṣiṣẹ siwaju

Faith Adebọla, Eko Ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹjidinlogun, oṣu yii, lawọn oṣiṣẹ ijọba ipinlẹ Eko ti n gbaradi lati…

Nitori Jẹgẹdẹ, ẹgbẹ PDP kọju ija sira wọn l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkan-o-jọkan oko ọrọ lawọn asaaju PDP ipinlẹ Ondo n sọ lu ara wọn…

Ki laa ti waa ṣeyi si, awọn Fulani tun pa agbẹ meji n’Igangan

Ọlawale Ajao, Ibadan O kere tan, eeyan meji lo ku, tọpọ eeyan si fara pa nigba…

Ajiṣafẹ dero ẹwọn, orukọ ọga FRSC lo fi lu jibiti l’Omu-Aran

Stephen Ajagbe, Ilorin Ajiṣafẹ Tokunbọ, oṣiṣẹ ajọ to n mojuto igboke-gbodo ọkọ, FRSC, tẹlẹ, ti wa…

Lẹyin ti wọn dana sun ẹni kan laaye, wọn tun yinbọn paayan mi-in n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Laarin wakati mélòó kan sira wọn, èèyàn meji ni won ti pa nipakupa…

Fidio: Ẹ woju Aafaa Awayewaserere to n ra ori eeyan niluu Iwo

Orukọ ko ro ọkunrin to pe ara rẹ ni Aafaa Awayewaṣerere yii o. Ẹ gbọ iye…

Eyi nidi ta a fi le awọn ẹṣọ Amọtẹkun meje danu n’Ibadan- Ọlayinka

Ọlawale Ajao, Ibadan   Oludari ikọ ẹ̣sọ eleto aabo ilẹ Yoruba, Amọtẹkun, ẹka ipinlẹ Ọyọ, Ajagunfẹyinti…

Igbimọ oluwadii ifiyajẹni SARS ni kawọn ọlọpaa mẹrin fara han kiakia l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Igbimọ tijọba ipinlẹ Ọṣun gbe kalẹ lati ṣewadii oniruuru ẹsun ti awọn araalu…

Awọn ajinigbe ji oṣiṣẹ-fẹyinti gbe ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin Lẹyin ọjọ kan tawọn ajinigbe ji Hakeem Ojo pẹlu baba agbalagba kan lọna…

Gomina gboriyin fawọn obinrin to dawo kọ ileewe ni Kwara

Stephen Ajagbe, Ilorin   L’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, Gomina Abdulrahman Abdulrazaq tipinlẹ Kwara ṣabẹwo si ileewe…

Akẹkọọ Fasiti ipinlẹ Eko mẹta lugbadi Korona, lawọn alaṣẹ ba ti ile ti wọn n gbe pa

Faith Adebọla, Eko Latari bi esi ayẹwo ti wọn ṣe fawọn kan lara awọn akẹkọọ Fasiti…