Awọn mẹrin to n fojubọ lu jibiti ti wọn tun n fọ ayederu owo n’Ijẹbu-Ode bọ sọwọ ọlọpaa

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ojubọ arumọjẹ kan wa lagbegbe Ijagun,nitosi Ijẹbu-Ode, nipinlẹ Ogun, inu igbo jingbun ni, awọn…

Tẹgbọn-taburo ti wọn n ṣe ‘Yahoo’ l’Oṣogbo ko sọwọ EFCC

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Akinrinmade Adepọju Sunday ati aburo rẹ, Akinrinmade Adeniyi, ni ọwọ awọn oṣiṣẹ ajọ…

Lasiko tawọn adigunjale meji fẹẹ bọ Ogun nitori ibọn wọn lawọn ọlọpaa ka wọn mọ l’Ejigbo

Faith Adebọla, Eko   Ibi tawọn afurasi adigunjale meji kan, Ọpẹyẹmi Adegboyega, ẹni ọdun mejidinlọgbọn, ati…

Ọjọ mẹfa ni mo fi sun inu igbó lahaamọ awọn Fulani ajinigbe- Alaga kansu

Ọlawale Ajao, Ibadan   Alaga ijọba ibilẹ onidagbasoke Iganna, lagbegbe Ibarapa, nipínlẹ Ọyọ, Ọnarebu Ọlayiwọla Adeleke,…

Dubai lawọn eleyii ti waa ṣe ‘Yahoo’ l’Ekoo ti EFCC fi mu gbogbo wọn

Faith Adebọla, Eko   Orileede United Arab Emirates, ti Dubai jẹ olu-ilu rẹ, ni wọn lawọn…

”Igbẹ lawọn Fulani to ya wọ lbarapa waa dẹ lati ipinlẹ Kebbi”

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọpọ èèyàn niṣẹlẹ ọhún ko laya soke nigba ti iroyin lu jade pe…

Kọmiṣanna ọlọpaa Eko ṣekilọ fawọn ọba alaye: Ẹ yee ṣonigbọwọ fawọn ọmọ ẹgbẹ okunkun

Faith Adebọla, Eko       Kọmiṣanna ọlọpaa ipinlẹ Eko, CP Hakeem Odumosu, ti fi aidunnu…

Ọọni Adeyẹye ranṣẹ ikilọ pataki si Sunday Igboho

Jide Alabi   Pẹlu bi nnkan ṣe n lọ yii, Ọọni Ile-Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ogunwusi, ti…

Peter sọ fawọn ọrẹ ẹ pe ọga oun lowo lọwọ, n l’Arowolo atawọn ẹgbẹ ẹ ba lọọ digun ja a lole l’Ekoo

Aderounmu Kazeem   Bii ajẹ to jẹ̣ eepo ọbọ ni ọdomọkunrin kan, Arowolo Ibrahim, ṣe n…

Lucky ati Sheriff, ọmọ ẹgbẹ okunkun Ẹiyẹ, ko sọwọ ọlọpaa n’lkorodu

Faith Adebọla, Eko     Ọwọ ọlọpaa ti ba awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun meji kan, Sheriff…

Awakọ pa oṣiṣẹ LASTMA l’Ekoo

Jide Alabi L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii ni ẹṣọ agbofinro to n dari ọkọ, iyẹn LASTMA pade…