Mariam fun ọmọ iyawo ẹ ni majele jẹ l’Ẹdẹ, o l’eṣu lo ti oun toun fi pa a

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Iyaale ile kan, Musa Mariam, ti sọ pe eṣu lo ti oun ti…

O ma waa ga ọ! Wọn tun ji agbẹ mi-in gbe n’Igangan

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọjọ mẹta ti wọn ji gbajumọ oniṣowo epo rọbi gbe niluu Idere,…

Ẹ wo Akanji, ọmọ ẹ lo fipa ba lo pọ l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Akanji Oluwaṣeyi ni baba ti ẹ n wo yii n jẹ, ẹni ọdun…

Bolu to fọ ile purofẹsọ l’Ado-Ekiti ti dero kootu

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ọkunrin ẹni ọdun marundinlogoji kan, Bolu Ojo, ti dero kootu Majisreeti to wa…

O ma waa ga o! Wọn tun ji agbẹ mi-in gbe n’Igangan

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọjọ mẹta ti wọn ji gbajumọ oniṣowo epo rọbi gbe niluu Idere…

Wasiu kọ iyawo ẹ silẹ n’Ibadan, o ni imukumu ẹ ti pọ ju

Igbeyawo Abọsẹde Adesọnwo ati ọkọ ẹ, Wasiu, ti daru n’Ibadan, ipinlẹ Ọyọ, lori ẹsun imukumu ti…

Posita Ṣẹgun Oni gba igboro kan l’Ekiti, wọn lo tun fẹẹ ṣe gomina lẹẹkan si i

Kazeem Aderounmu Kaakiri awọn ilu kan nipinlẹ Ekiti lawọn eeyan ti n ri posita Enjinnia Ṣẹgun…

Wahala mi-in tun n bọ laarin ASUU ati ijọba apapọ 

Awọn oloye ẹgbẹ olukọ Yunifasiti, iyẹn ASUU, ti sọ pe awọn ṣi n duro de owo…

Tinubu lẹtọọ daadaa lati di aarẹ, ṣugbọn… Ọṣọba 

Gomina ipinlẹ Ogun nigba kan ri, Arẹmọ Oluṣẹgun Ọṣọba, ti sọ pe gbogbo ẹtọ pata ni…

Jumọkẹ binu para ẹ l’Ondo, nitori ti wọn fun un niwee gbele ẹ lẹnu iṣẹ

Jide Alabi Titi di asiko yii ni iku oro ti ọmọbinrin kan, Jumọke Kẹhinde, ti ko…

O san keeyan gbagbe nipa ijọba to wa lode yii patapata –Ṣoyinka

Faith Adebọla Ogbontarigi ọmọwe ati onkọwe ilẹ wa nni, Ọjọgbọn Wọle Ṣoyinka, ti sọ pe o…