Stephen Ajagbe, Ilorin Awọn araadugbo Adeta, niluu Ilọrin, ti fa afurasi ẹni ọdun marundinlọgbọn kan, Isiaka, tọwọ…
Category: Ìròyìn
Awọn ti mi o ba rowo ji nile wọn ni mo maa n ba iyawo tabi ọmọọdọ wọn lo pọ – Adeniyi
Faith Adebọla, Eko “Ẹ wo o, lati oṣu kin-in-ni, ọdun 2019, lemi ti n digunjale, mi…
Akẹkọọ Fasiti Ilọrin rẹwọn oṣu mẹsan-an he fẹsun jibiti
Stephen Ajagbe, Ilorin Adajọ Sikiru Oyinloye tile-ẹjọ giga kan niluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, ti sọ akẹkọọ…
Ọọni yoo gbe igbesẹ lori iwọde tawọn oṣiṣẹ-fẹyinti ṣe nitori Oyetọla
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọọni tilu Ileefẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi, ti ṣeleri lati da si ọrọ…
Ajọ iṣọkan agbaye fẹẹ kọ ẹgbẹrun lọna aadọta ile s’Ekiti
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ẹka ajọ iṣọkan agbaye to n ri si iṣẹ akanṣe (UNOPS) ti bẹrẹ…
Koronafairọọsi: Ofin konilegbele n palẹmọ diẹdiẹ l’Ekiti
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Lalẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee to kọja, ni Gomina Kayọde Fayẹmi tipinlẹ Ekiti kede…
Ọrọ yii ṣi maa dija: Wọn ti gba APC lọwọ Tinubu o
Nigba ti alaga igbimọ awọn gomina ẹgbẹ APC, Atiku Bagudu to tun jẹ gomina ipinlẹ Kebbi…
Olori oṣiṣẹ Gomina Zulum tipinlẹ Borno jade laye
Olori oṣiṣẹ Gomina Babagana Zulum tipinlẹ Borno, Babagana Wakil, ti jade laye. Wakil lo jẹ Ọlọrun…
Ijọba apapọ fi kun owo-epo bẹntiroolu
Ijọba apapọ ilẹ Naijiria ti fi kun owo epo bẹntiroolu, eyi to gbera kuro ni naira…
Awọn ẹruuku tun ya wọ Akinyẹle, n’Ibadan, wọn ṣa iya atọmọ ladaa
Ọlawale Ajao, Ibadan Pẹlu bi awọn ẹni ibi kan ṣe n pa awọn eyan nipakupa lagbegbe Akinyẹle, n’Ibadan, awọn…
Ọwọ tẹ Tọpẹ nibi to ti n fọle onile l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Diẹ lo ku ki wọn dana sun afurasi adigunjale kan, Tọpẹ Owolabi, tọwọ…