Ewe sunko! Oogun afẹẹri ti Ọlalekan ṣe lati gbe egboogi oloro kọja ni ẹẹpọọtu ko ṣiṣẹ

Faith Adebọla  Niṣe ni ọkunrin afurasi ọdaran yii, Imran Taofeek Ọlalekan, ẹni ọdun mẹrinlelogoji (44), lanu…

Aadọta miliọnu lawọn ajinigbe to ji akẹkọọ Fasiti Taraba meji n beere fun

Adewale Adeoye Miliọnu lọna aadọta Naira (N50M) lawọn ajinigbe kan ti wọn ji akẹkọọ ileewe Fasiti Taraba ‘Federal University’, to wa lagbegbe Wukari, nipinlẹ Taraba, n beere…

Lẹyin ti baale ile yii pa iyawo ẹ tan loun naa gbe majele jẹ

Adewale Adeoye Ha-in lọrọ oṣiṣẹ banki kan, Oloogbe Mike Illishebo, ẹni ọdun mẹrinlelogoji, to pa iyawo rẹ,  Valeria Franco, ẹni ọdun marundinlogoji, ṣi n…

Ojo nla ṣọṣẹ ni Poli Ekiti, ọpọlọpọ nnkan lo bajẹ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Kayeefi nla lo jẹ fun gbogbo eeyan ipinlẹ Ekiti l’Ọjọbọ, Wẹsidee, ọjọ kẹta,…

Ọpọlọpọ egboogi oloro ti ọmọkunrin yii fẹẹ gbe sọda siluu oyinbo lo ti ya jade lakata NDLEA

Monisọla Saka Ọwọ ajọ to n gbogun ti tita, rira ati lilo egboogi oloro nilokulo lorilẹ-ede…

Ibọn onike lawọn eleyii fi n jale tọwọ fi tẹ wọn

Adewale Adeoye Ọdọ awọn ọlọpaa agbegbe Isọkoko, ni Agege, nipinlẹ Eko, lawọn gende meji kan, Kyari Idris, ẹni ogun ọdun, ati Abubarkar Salisu, ẹni ọdun mejidinlogun wa. Ẹsun ti wọn…

Nitori foonu, ṣọja ati olotẹẹli fiya jẹ ọmọkunrin yii titi to fi ku

Monisọla Saka Ọwọ awọn agbofinro ipinlẹ Imo ti tẹ Ọgbẹni Ibe Obasi, ọkunrin to ni ile…

Ijọba apapọ kede ọjọ Iṣẹgun ati Ọjọruu gẹgẹ bii isinmi ọdun itunu aawẹ

Adewale Adeoye Ijọba orileede Naijiria ti kede ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kẹsan-an, ati Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ…

Eyi lawọn ohun to yẹ ki ẹ mọ nipa afikun owo ina mọnamọna

Monisọla Saka Ileeṣẹ to n ri si ọrọ ina mọnamọna lorilẹ-ede yii, Nigerian Electricity Regulatory Commission…

‘’Iya gidi ni yoo jẹ ọlọpaa to ba yẹ foonu araalu wo loju titi’’

Monisọla Saka Ileeṣẹ ọlọpaa ilẹ wa, ẹka ti ipinlẹ Edo, ti ṣe e leewọ fawọn agbofinro…

Wọn ti mu Pasitọ James to lu ọmọ ijọ rẹ ni jibiti owo nla n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọwọ ajọ to n gbogun ti iwa ibajẹ ati ṣiṣe owo ilu mọku-mọku…