Ina ṣẹ yọ ninu ileewosan ijọba ipinlẹ Eko to wa n’Ikeja

Adewale Adeoye Ni nnkan bii aago meji kọja ogun iṣẹju Ọjọbọ, Tọsidee, ọjọ kẹrin, oṣu Kẹrin, ọdun yii, ni ina ṣẹ yọ…

Nitori ẹran maaluu, Sunday fi okun fun ọrẹ iyawo rẹ lọrun pa l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọkunrin ẹni ọdun marundinlogoji kan, James Sunday, ti n jẹjọ nile-ẹjọ Majisireeti to…

Mi o ba ẹnikankan sọ pe mo ko arun ibalopọ lara ọkọ mi-Iyawo Mohbad

Adewale Adeoye Wunmi Alọba ti i ṣe iyawo Oloogbe Ilerioluwa Alọba, ẹni tawọn eeyan mọ si Mohbad, ti sọ pe oun ko figba kankan sọ fẹnikẹni ri…

Sunday Igboho b’Alaroye sọrọ: Eyi nidi ti mo fi gbe Gani Adams lọ sile-ẹjọ

Jọkẹ Amọri Ajijagbara ọmọ Yoruba nni, Oloye Majasọla Sunday Adeyẹmọ, ti gbogbo eeyan mọ si Sunday…

Aṣiri tu! Ọwọ tẹ ayederu EFCC, ọpọ araalu lo ti lu ni jibiti n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akolo ajọ to n gbogun ti iwa ibajẹ ati ṣiṣe owo ilu mọku-mọku…

Iwakusa lọna aitọ yoo dopin tijọba apapọ ba n ṣewadii awọn ileeṣẹ ti wọn n fun ni lansẹnsi – Fakẹyẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oludamọran pataki fun gomina ipinlẹ Ọṣun lori ọrọ iwakusa, SP Olumuyiwa Fakẹyẹ, ti…

Ẹni Ọlọrun o pa! Inu igbo ti wọn ju ọmọ tuntun yii si ni aja ti fẹnu gbe e wọlu

Monisọla Saka Ẹni ti Ọlọrun ko pa ko kuku ni i ku lọrọ ọmọ tuntun jojolo…

O ṣẹlẹ! Wọn ni ayederu iwe-ẹri ileewe girama ni gomina Ondo n gbe kiri

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kete ti Ọnarebu Lucky Orimisan Ayedatiwa ti gba ọpa aṣẹ gẹgẹ bii gomina…

Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ si Bobrisky lọfiisi awọn EFCC?

Faith Adebọla Boya ni ọkunrin to ti fẹẹ sọ ara ẹ di obinrin tan, to gbajumọ…

Eeyan kan dero ọrun nibi ija agba awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun n’llọrin 

L’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ kẹta, oṣu Kẹrin ọdun 2024 yii, ni ọrọ di bo o lọ o…

Awọn agbebọn tun ji akẹkọọ fasiti meji gbe sa lọ  nipinlẹ Taraba

Adewale Adeoye Meji lara awọn akẹkọọ ileewe giga ‘Federal University’,  to wa lagbegbe Wukari, nipinlẹ Taraba, Joshua Sardauna ati Obianu Elizabeth, ni awọn…