Michael Adunọla ti fara han niwaju ile-ẹjọ Majisreeti ilu Ileefẹ lori ẹsun pe o pa iyawo…
Category: Ìròyìn
Ile-ẹjọ sọ awọn ọmọ orileede India meji to n ji epo rọbi satimọle
Faith Adebọla, Eko Afaimọ kawọn ọmọ ilẹ India meji yii, Akash Kumar ati Vishal Guleria ma…
IDAAMU OLUWOO: Ọba to ti ṣẹwọn l’Amẹrika nigba kan
Loootọ ni Ọba naa ti n jagun tipẹ, bo tilẹ jẹ pe ọpọ ogun naa jẹ…
Sunday ọlọkada gbe ọmọ ẹgbẹ okunkun pẹlu ibọn n’Ijẹbu-Ode, ni wọn ba ko sọwọ ọlọpaa
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bo tilẹ jẹ pe Sunday Francis, ọlọkada ẹni ọdun mejidinlogoji (38) n’Ijẹbu-Ode, sọ…
Oogun oloro: Ajọ NDLEA ṣekilọ fawọn ọdaran lẹyin tọwọ tẹ mọkandinlaaadọfa
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Adari ajọ to n gbogun ti oogun oloro nilẹ yii (NDLEA), ẹka tipinlẹ…
Olusin tilu Isanlu-Isin rọ oloye kan loye, niyẹn ba ni awada lasan ni
Stephen Ajagbe, Ilorin Nitori iwa ijọra ẹni loju, jagidijagan ati dida ilu ru, Olusin tilu Isanlu-Isin,…
Ta lo n purọ: Owo dija silẹ laarin Gomina Makinde ati ileewosan UCH
Ọlawale Ajao, Ibadan Gbogbo aye lo n fi ijọba ipinlẹ Ọyọ atawọn alaṣẹ UCH, iyẹn ileewosan…
Kayeefi nla leleyii o! Baba fun ọmọ bibi inu ẹ ẹ loyun n’Ikorodu
Chibuike naa tun fipa bọmọ ọdun mẹrinla lo pọ ni Bariga Bẹẹ ni Chinedu ṣe kinni…
Eyi ni bi aarẹ ẹgbẹ Rotaract Club ilu Iwo ṣe ku nibi to ti n gba bọọlu
Florence Babaṣọla, Osogbo Bii ala lọrọ naa ṣi n jẹ loju gbogbo awọn eeyan ilu Iwo,…
Wọn ṣi n wa awọn arinrinajo mẹjọ ti wọn ji gbe ni Akoko
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Titi di ba a ṣe n sọ yii lawọn agbofinro atawọn ẹṣọ alaabo lẹlẹka-jẹka ṣi…
Ajọ OYTMA gbẹsẹ le mọto ijọba ipinlẹ Ọyọ, wọn lo da gosiloo silẹ
Ọlawale Ajao, Ibadan “Bi gbogbo aye ba n ṣe bayii, a dun”. Eyi lọrọ ti ọpọ…