O ṣẹlẹ, ile-ẹjọ ni Baruwa ni ojulowo aarẹ ẹgbẹ onimoto  l’Abuja

Adewale Adeoye Ẹsẹ ko gbero ni kootu ajọ oṣiṣẹ, ‘National Industrial Court’, to wa niluu Abuja, ti i ṣe olu ilẹ wa, lọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kọkanla, oṣu Kẹta, ọdun 2024 yii, lasiko ti…

Ọga ọlọpaa, ọba alaye atawọn adari ẹṣin ni yoo ṣeto pinpin ounjẹ iranwọ faraalu ni Kwara – AbdulRazaq 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Gomina ipinlẹ Kwara, Abdulrahaman AbdulRazaq, ti gbe igbimọ kan kalẹ lati ṣeto pinpin…

Nitori ọmọbinrin kan, Sanwo-Olu gbaṣẹ lọwọ ọga LASIAMA atawọn manija ẹ

 Faith Adebọla Titi dasiko yii ni awuyewuye ṣi n lọ lori iku Dokita kan, Arabinrin Vwaere…

Esther ati David lu oniṣowo kan ni jibiti ẹgbẹrun lọna irinwo ($400,000)dọla

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn jaguda meji kan, Esther Shehu ati David Kpanaki, ni awọn alaṣẹ ileeṣẹ…

Eyi lawọn eeyan tijọba Buhari tori ẹ paarọ owo ilẹ wa

Ọrẹoluwa Adedeji Pẹlu bi awọn araalu ṣe n to rẹrẹẹrẹ lawọn banki kaakiri ilẹ wa lati…

Adeleke gbọpa aṣẹ l’Ọṣun

Florence Babaṣọla ati Faith Adebọla Ọjọ pataki ti ọpọ eeyan ti n reti lọjọ Aiku, Sannde,…

Itan igbesi aye Alaafin Adeyẹmi

Yẹmi Adedeji Nibi ti ilu Ọyọ wa loni-in yii kọ lo wa tẹlẹ, Ọyọ meji ti…

Miyetti Allah parọwa sawọn Fulani darandaran: Ẹ fi ilẹ Yoruba ati Ibo silẹ fun wọn o, ẹ maa bọ nile

Faith Adebọla Ẹgbẹ awọn darandaran onimaaluu ilẹ Hausa, Miyetti Allah Cattle Breeders’ Association of Nigeria (MACBAN),…

GỌNGỌ SỌ NILUU ẸRINMỌ

GỌNGỌ SỌ NILUU ẸRINMỌ  

Ìtàn ìgbésí ayé Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ Ori Kẹta (Apa Keji).

ki o le je ẹkọ fun ọmọ Yoruba gbogbo. Ọdun 2019 ni a ti tẹ iwe…