IYA BIỌLA Igbeyawo Akin ti a ṣe laipẹ yii, a kuku tun ti fi da nnkan…
Category: Ìyá Bíọ́lá
Igbeyawo Akin: Ṣe aye mi daa tabi ko daa
A ti lọọ tọrọ iyawo Akin. N ko le sọ pe o dun mi tabi ko…
Ẹjọ ni pasitọ yii fẹẹ ro, ọrọ lo si maa fi gbọ
Ẹ wo o, o daa ki eeyan naa daa. Bi eeyan ba daa, toun naa jẹ…
Wọn ma fọlọpaa mu ọmọ mi o
Emi o le fi taratara da si ọrọ awọn Sẹki yẹn, ọrọ lọkọ-laya ni, nigba tẹni…
Alaaji ti waa fọgbọn tuuba, a ti tun dọrẹ pada
Alaaji, agbaaya, o kuku mọ bi oun ti ṣe n mu mi. Oun naa mọ pe…
Oyinbo muti, ọti n pa kuku
Ọlọrun ma jẹ ki wọn mu baba yin lọ. Emi kuku ti kilọ fun un, Ọlọrun…
Ẹ ba mi dupẹ, Sẹkinatu Abẹjẹ, ọmọ mi ti bimọ o
Ẹ wo o, nnkan ti waa bajẹ patapata. Ọrọ aye yii, ti mo ba ni ki n…
Ibinu Alaaji bii ibinu Abija, Ọlọrun ma jẹ n ri i
Ka ṣa maa ṣe rere. Ṣe ẹ mọ pe gbogbo igba ni mo maa n wi…
Ani, aa ranti tilẹkun ṣọọbu lọjọ ofin konilegbele
Ọrọ Aunti Sikira ati ọkọ ẹ ni mo n yanju nigba ti wahala to ṣẹlẹ lọṣẹ…
Aunti Sikira jẹwọ fun mi, o ni loootọ lọkunrin yẹn boun ṣe aṣemaṣe
Eke niyaale mi, Iya Dele. Eke gidi ni. Abi bawo lo ṣe mọ pe panti ti…
Bẹẹ ki i ṣe eleyii ni yoo gbe Anti Sikira kuro nile Alaaji
Niṣe ni mo n bẹ Safu ko ma sọ ọrọ ilẹ ẹ ti a lọọ ra…