Safu ti ra ilẹ si Mowe, Ọlọrun ni i ṣọla loootọ o

Ẹ ẹ wa gba mi! Oniranu! Ọmọkunrin kan bayii ma ni o. Awọn ọmọ ti wọn…

Safu loun o fẹ mọto, ọtọ lohun ti ọmọ mi fẹ

Iya Tọmiwa naa waa ki mi o. O kuku wa. Tiẹ lo si ya mi lẹnu…

Emi ati awọn tẹnanti mi ti ṣepade, faaji la fi pari ẹ

Nigba ti mo de ṣọọbu ti mo royin ohun to n ṣẹlẹ nile, ti mo sọ…

Ẹ ba mi bẹ wọn ki wọn ma pa baba yii fun mi

Mo n wa oogun ti mo maa maa fun Alaaji lo, oogun ti ko ni i jẹ ki aarẹ mu un. Nitori…

Lalẹ ọjọ ti mo ra ilẹ Oṣodi yẹn, gobe ṣẹlẹ nile wa

Alaṣepe ni Ọba Ọlọrun. Nigba to ba ṣe tan lati ṣe oore fun ẹda, yoo ṣe kinni…

Ọrọ ilẹ ti yanju, ẹ ba mi gbadura ki Ọlọrun falubarika si i

Ẹ wo o, ki ire Ọlọrun ma jinna si gbogbo wa. Gbogbo ohun ti a n wa yii, gbogbo…

Ẹ ẹ ri i pe iṣẹ Ọlọrun yii ko ṣee tu wo, Ọba alaṣepe ni

Gbogbo ọna ni ọkan mi fi balẹ, nitori awọn iṣẹ ti kaluku n jẹ fun mi…

Ọlọrun oju ẹ da, Ọba to tobi ni ọ o!

Bi mo ṣe fẹẹ jade nile ni mo pade Sẹki, mo fẹẹ maa sọ pe ṣe…

Ni bayii, ọrọ ile Oṣodi yii lo wa lọkan gbogbo wa

Mo mọ nnkan temi, mo mo bo ṣe maa n ri. Ti mo ba ti fẹẹ…

Ẹ ba mi dupẹ lọwọ Alaaji, ọkọ mi ti ṣadura fun mi

Nigba ti Safu ti sọ pe ki n fọkan si i, n oo ra ile Oṣodi…

Emi naa ti gba bẹẹ: Oriire ki i jinna sẹni to ba n ṣe rere

Ki eeyan ṣaa maa ṣe suuru, ko si gbọkan le Oluwa Ọba. Ko si asiko ti…