Awọn nnkan kan wa ti mo ti kọja, n ko si ni i gba ẹnikẹni laaye…
Category: Ìyá Bíọ́lá
Safu halẹ mọ Alaaji, ni dadi wa ba n sare kiri
Baba ti jẹ ẹ tan! Wọn ti gẹẹti baba yin patapata. Alaaji ni, wọn ni kinni…
Laelae, emi o ni i da sọrọ Alaaji atawọn iyawo ẹ mọ o
Alaaji ti n dagba. Fun odidi ọjọ mẹta, ko jade, ere egele toun atawọn iyawo ẹ…
Safu ni Iya Dele at’Anti Sikira fẹẹ gbooru ara ninu ojo ni
Ọjọ keji ni mo too le ṣalaye ohun to ṣẹlẹ nile fun Safu. Nigba ta a de…