Ẹru kan wa to n ba mi o

Mo fẹ ki a jọ yẹ awọn kinni wọnyi wo, ko ma da bii pe emi…

Loootọ lọootọ ni mo wi fun yin, ijọba yii o daa!

Ohun ti awọn eeyan kan n sọ, ti wọn si n beere lọwọ mi bayii, ni…

Iyatọ diẹ lo wa ninu Trump Amẹrika ati Buhari Naijiria    

O da mi loju pe ọpọ awọn ọmọ wa, ati awọn ti wọn jẹ agba paapaa…

Bi irọ ba lọ logun ọdun… (2)

Eyi ti mo fẹẹ sọ yii ki i ṣe wọn ni wọn pe o, ohun to…

Bi irọ ba lọ logun ọdun…

Nigba ti rogbodiyan yii rọlẹ diẹ lọjọ Sannde, ti mo n wa nnkan ti mo le fi…

Ta lo fẹẹ ran iran Yoruba wa yii lọwọ o (2)

Ohun ti mo n wi lo n ṣẹlẹ lọwọlọwọ bayii o. Wọn ti ko ṣọja si…

Ta lo fẹẹ ran iran Yoruba wa yii lọwọ o

Wahala yin pọ ju! Awọn kan to jẹ ti mo ba ti darukọ Bọla, tabi ti…

Ẹyin Ọlọrun Yoruba, nibo lẹ wa, ẹ dide o (3)

Igba kan wa to jẹ n o le sọrọ laaarin oṣu kan loju iwe mi yii…

Ki lo de tawọn eeyan yii n sọ ominira di inira fun wa

A fẹran lati maa fi ara wa ṣe yẹyẹ ju. Mo wa ọrẹ mi kan lọ…

Ẹyin Ọlọrun Yoruba, nibo lẹ wa, ẹ dide o! (2)

Kin ni idi ti mo ṣe sọ pe awọn oloṣelu ti wọn jẹ ọmọ Yoruba tiwa…

Ẹyin Ọlọrun Yoruba, nibo lẹ wa, ẹ dide o!

N ko fẹẹ sọrọ lori ohun ti Bọla ṣe fun Ọọni Ifẹ ti gbogbo wa ri…