set feature image

Pelu bi eto ọrọ-aje ṣe denukọlẹ, ijọba mi ko ni i gbaṣẹ lọwọ oṣiṣẹ kankan- Akeredolu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Lasiko to n sinu aawẹ pẹlu awọn Musulumi lalẹ ọjọ Aiku, Sannde ọsẹ yii, ni gbọngan asa igbalode Doomu, to wa loju ọna Igbatoro, niluu Akurẹ, ni Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu, ti sọ pe oun ko ṣetan lati gba iṣẹ lọwọ eyikeyii ninu awọn oṣiṣẹ ijọba …

Read More »

Amotẹkun ti mu awọn Fulani to fipa ba awọn obinrin ti wọn ji gbe lo pọ l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn ajinigbe mẹrin kan lọwọ ẹsọ Amọtẹkun ipinlẹ Ondo tẹ niluu Akurẹ lọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ ta a wa yii. ALAROYE gbo pe Alakooso wọn nipinlẹ Ondo, Oloye Adetunji Adelẹyẹ, ni lọjọ Ẹti, Furaidee, ọsẹ to kọja, lawọn ti n tọpasẹ awọn ajinigbe ọhun lẹyin ti wọn …

Read More »

Awọn ọba Amosun yari fun igbimọ Oloye Kemta, wọn lawọn o ki i ṣe baalẹ, Tẹjuoṣo naa loun ṣi ni Olu Orile-Kemta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Latari bi igbimọ Oloye Kemta(Kemta Council Of Chiefs) nipinlẹ Ogun, ṣe ni awọn ti yọ Ọba Adetokunbọ Tẹjuoṣo nipo baalẹ tawọn fi i jẹ, ti wọn tun ni awọn baalẹ marundinlọgọrin ti Sẹnetọ Ibikunle Amosun sọ di ọba lọdun 2019 ki i ṣe ọba, awọn tọrọ naa …

Read More »
//ugroocuw.net/4/4998019