O ma ṣe o! Lẹyin oṣu marun-un ti wọn ṣegbeyawo, mọto pa ọkọ atiyawo toyun-toyun

Awọn iṣẹlẹ kan ki i ye eeyan to ba ṣẹlẹ, eeyan yoo kan maa wo o…

Lọdun 2020, baale ile mejidinlaaadọrun-un lo fẹjọ sun pe iyawo awọn lu wọn lalubami l’Ekoo – Ijọba

Faith Adebọla, Eko Bii apara lọrọ naa jọ, ṣugbọn ki i ṣe awada rara, ijọba ipinlẹ…

Awọn agbebọn pa ọlọpaa kan, wọn ji ikeji ẹ atawọn eeyan mẹta mi-in gbe l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Njẹ ẹ ti gbọ? Pe awọn agbebọnrin, ajinigbe, ti fi kun ọwọ ija…

Adekunle ko sọwọ ajọ NSCDC ni Kwara, maṣinni iranṣọ lo lọọ ji ko

Stephen Ajagbe, Ilorin Afurasi ẹni ọdun mẹrindinlaaadọta kan, Adekunle Adeniyi, to n gbe l’Ojule kọkandinlogun, ladugbo…

Wọn maa too fawọn akẹkọọ Fasiti Greenfield naa silẹ – Sheik Gumi

Faith Adebọla Gbajugbaja aṣaaju ẹsin Musulumi l’Oke-Ọya nni, Sheik Ahmad Gumi, ti sọ pe kawọn obi…

A o ni i din owo-oṣu awọn oṣiṣẹ ku nitori ọrọ-aje to n ṣojojo- Gomina Dapọ Abiọdun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Latari ọrọ-aje orilẹ-ede yii to n ṣojojo, ti ijọba apapọ atawọn ipinlẹ kan…

Awọn ọdọ ṣewọde l’Ekiti, wọn lawọn o fẹ ‘Orileede Oodua’ ni tawọn

Faith Adebọla Awọn ọdọ kan, awọn ọlọkada ati ẹgbẹ awọn onimọto nipinlẹ Ekiti pe jọ si…

Nitori bi wọn ṣe tun pa eeyan meji, awọn ọdọ Ayetẹ lawọn o fẹẹ ri Fulani kankan mọ lagbegbe naa

Faith Adebọla Iwọde nla kan la gbọ pe o n lọ lọwọ lasiko yii ni ilu…

Oko ole ni Rasheed ati Matthew n lọ tọwọ fi tẹ wọn l’Ọta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Rasheed Ayinde; ẹni ogun ọdun, ati Matthew  Ọladipupọ, ẹni ọdun mẹtalelogun, lẹ n wo…

Obitibiti igbo atawọn oogun oloro mi-in ni wọn ba nile iya arugbo yii ati ọmọọmọ ẹ l’Akurẹ

Faith Adebọla Kayeefi lọrọ naa n ṣe awọn eeyan, ọpọ lo si n beere pe kin…

Ọdaju abiyamọ sọmọ oṣu mẹfa yii nu, awọn alaaanu kan lo ri i he

Faith Adebọla, Eko Bi ko ba si ti awọn alaaanu kan ti Ọlọrun fi ṣe kongẹ…