Ijọba apapọ yan ipinlẹ Ogun lati janfaani oriṣii mẹta labala ọgbin

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Wọn ti yan ipinlẹ Ogun gẹgẹ bii ilu ti yoo jẹ anfaani ọna…

Tẹjuoṣo ki i ṣe ọba, a si ti yọ ọ nipo baalẹ ta a fi jẹ pẹlu- Igbimọ Baalẹ Kemta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta ‘Kemta Traditional Council of Chiefs’ iyẹn igbimọ to n ri si ọrọ oye…

O ma ṣe o, ọmọ Baba Adeboye lọkunrin ku lojiji

Agbọ-sọgba-nu ni iroyin iku Pasitọ Dare Adeboye, ọkan ninu awọn ọmọ Pasitọ ijọ Ridiimu, Enock Adeboye,…

Nitori rogbodiyan to n lọ lọwọ n’Ikarẹ Akoko, ijọba paṣẹ konilegbele

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akure Ijọba ipinlẹ Ondo ti kede ofin konilegbele oni wakati mẹrinlelogun latari rogbodiyan to…

Bi Naijiria ba fi le pin, iya gidi ni yoo jẹ awọn ẹya keekeeke-Ọbasanjọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta L’Ọjọruu, ọjọ karun-un, oṣu karun-un, ọdun 2021, awọn akọṣẹmọṣẹ lati ilẹ TIV, ni…

Lẹyin oṣu meji, wọn da awọn ọmọleewe Kaduna ti wọn ji gbe silẹ

Faith Adebọla Aja to re’le ẹkun to bọ, ka ki i ku ewu ni, lẹyin to…

Miliọnu kan aabọ ‘irẹṣi Tinubu’ ni wọn n ha lọwọlọwọ bayii nilẹ Hausa

Faith Adebọla, Eko Pitimu lawọn eeyan lapa Oke-Ọya n ya bo awọn ibudo ti wọn ti…

Ọpẹyẹmi gun iya iyawo ẹ pa l’Atan-Ọta, o lo da sija oun atọmọ ẹ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi ẹni lu iya iyawo ba ṣe diẹ nile ana, ẹni to waa…

Ayọ abara tintin, obinrin yii bi ọmọ mẹsan-an lẹẹkan!

Faith Adebọla A ti n gbọ iya ibeji, iya ibẹta, iya mẹrin, ṣugbọn oore kẹnkẹ to…