Adajọ ni ki wọn yẹgi fun Quareem to pa fijilante mẹrin ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu  Ile-ẹjọ giga kan to fi ilu Ilọrin ṣe ibujokoo, ti pasẹ pe ki wọn…

Ọdun Ileya: Ijọba kede ọjọ Aje ati Iṣẹgun fun isinmi lẹnu iṣẹ

Faith Adebọla Latari pọpọ ṣinṣin ọdun Ileya, Eid-el-Kabir, to gbode, ijọba apapọ ti kede ọjọ Aje,…

Wọn ti mu Adetunji ati Ọpẹyẹmi to ji ẹran Ileya Sọdiq gbe l’Ogijo

Gbenga Amos, Abẹokuta Bi ko ba jẹ pe o taji loju oorun nigba to n gbọ…

Nibi ti obinrin yii ti fẹẹ ji ọmọ gbe lọwọ ti tẹ ẹ n’Ikarẹ Akoko

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Diẹ lo ku ki wọn dana sun obinrin ajọmọgbe kan tọwọ tẹ n’Ikarẹ…

Baba ẹni ọdun mẹrindinlaaadọta dawati l’Ogbomọṣọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Inu ipayinkeke nidile Arẹo, niluu Ogbomọṣọ, wa bayii pẹlu bi ọkan ninu wọn, Oluṣẹgun…

Miliọnu marun-un lawọn agbebọn to ji Saheed n’Ilọrin n beere fun 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Awọn ajinigbe to ji Mallam Saheed Taiwo Olowududu gbe ni iwaju ile rẹ…

Wọn ni mo gbọdọ jo nihooho laarin abule tori mo yan ale, mi o le ṣe e, ẹ tu wa ka – Sandra

Faith Adebọla, Eko Ẹnu ara ẹni la fi n kọ ‘mi o jẹ,’ ni iyaale ile…

Awọn ọmọlẹyin Kristi darapọ mọ awọn Musulumi lati ro ilẹ Yidi

Monisọla Saka Awọn ọdọ kan atawọn agbalagba ti wọn jẹ ọmọlẹyin Jesu nijọba ibilẹ Kachia, nipinlẹ…

Ẹgbẹrun kọọkan Naira lalaisan yoo maa san fun ina ẹlẹntiriiki nileewosan UCH bayii

Ọlawale Ajao, Ibadan Yatọ si owo ti ileewosan ọhun n gba lọwọ awọn alaisan, ẹgbẹrun kọọkan…

L’Ọṣun, adajọ ju babalawo sẹwọn, wọn lo lu ẹnikan ni jibiti owo nla

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Adajọ ile-ẹjọ Majisreeti kan niluu Ileṣa ti paṣẹ pe ki babalawo kan, Kehinde…

A ko ni i faaye gba iwa janduku ati iyanjẹ latọwọ ẹgbẹ oṣelu APC Ọṣun mọ – PDP

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party (PDP) nipinlẹ Ọṣun ti ke si ajọ agbaye…