Ẹlẹwọn bii ẹgbẹta lo sa lọ ni Kuje, Abba Kyari atawọn ọdaran nla kan dawati

Faith Adebọla  Ko ti i daju boya awọn afẹmisofo Boko Haram, tabi ISWAP ni wọn, abi…

Eeyan meji ku nibi ijamba ọkọ oju omi l’Ekoo

Monisọla Saka Obinrin meji lo ti dero ọrun ninu ijamba ọkọ oju omi to ko ero…

Ọba ilu ṣegbeyawo pẹlu alegba, ni wọn ba fẹnu kora wọn lẹnu

Kayeefi nla ni ọrọ ọba ilu kan ti wọn n pe ni San Pedro Huwmelula, Victor…

Ọba ilu ‘ṣegbeyawo’ pẹlu alegba, ni wọn ba fẹnu ko ara wọn lẹnu

Kayeefi nla ni ọrọ ọba ilu kan ti wọn n pe ni San Pedro Huwmelula, Victor…

Nibi ti wọn ti n sa fun ọlọpaa, odo gbe ọlọkada meji lọ n’Igbara-Odo l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Awọn eeyan ilu Igbara-Odo Ekiti, nijọba ibilẹ Guusu Ekiti, ti wa ninu ọfọ…

Ọwọ tẹ awọn oni Maruwa to pa ọlọpaa n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Eeyan mẹsan-an ọtọọtọ lọwọ awọn agbofinro tẹ n’Ibadan fun ẹsun ipaniyan nikan. Eyi…

Ijakulẹ ba aadọjọ ninu awọn to fẹẹ lọ si Mẹka, ajọ alalaaji lo fọ wọn jẹ

Ọlawale Ajao, Ibadan O kere tan aadọjọ (150) ninu awọn to fẹẹ rin irin-ajo mimọ lọ…

Omi ni Fridauz lọọ pọn lodo to fi gan mọ’na n’Ilọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọmọdebinrin ẹni ọdun mejila kan, Fridauz, ti dero ọrun bayii pẹlu bo ṣe…