Nitori ati gba kaadi idibo, ijọba Eko kede isinmi ọlọjọ mẹrin lẹnu iṣẹ

Monisọla Saka Latari ati ri i pe gbogbo awọn olugbe ipinlẹ Eko ti wọn ti to…

Ibo 2023: Babalawo ati aafaa ṣe gbaju-ẹ fun aṣofin Ekiti, miliọnu mẹrinlelogun ni wọn gba lọwọ ẹ

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ọwọ ajọ to n gbogun ti lilu owo ilu ni ponpo ati iwa…

Buhari yii ko mọ nnkan kan mọ, ko sigba ti wọn ko ni i ji gbe lọ – Buba Galadima

Faith Adebọla Eekan oloṣelu apa Oke-Ọya ilẹ wa to ti figba kan jẹ alatilẹyin timọtimọ fun…

Inu oṣu Keje yii ni Ismail tẹwọn de to tun fi lọọ ji ọkada gbe ni Kwara

Ibrahim Alagunmu Akolo ajọ ẹsọ alaabo sifu difẹnsi, ẹka tipinlẹ Kwara, ni Wasiu Ismail ati awọn…

Wọn yọ orukọ Portable kuro lara awọn to fẹẹ gba awọọdu, wọn ni woroworo ẹ ti pọ ju

Faith Adebọla, Eko Latari bo ṣe n fẹnu ja waya kiri, to sọ pe oun loun…

Ọwọ ba mẹta ninu awọn to n ṣẹgbẹ okunkun l’Abẹokuta, olori wọn fara gbọta lọ

Gbenga Amos, Abeokuta Awọn afurasi ọdaran to n ṣẹgbẹ okunkun l’Abẹokuta ti pinnu p’awọn o ni…

Ẹgbọn gomina Ọṣun tuntun ni: Emi ni ma a kọkọ pariwo bi o ba yẹsẹ ninu ileri to o ṣe faraalu

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Dokita Deji Adeleke, to jẹ ẹgbọn gomina tuntun ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan…

Ọpọ dukia segbe nibi ijamba ina l’ọja Alanamu

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin O kere tan, sọọbu mọkanla lo jona, ti ọkẹ aimọye miliọnu si segbe…

Ọlọpaa ati Fulani kan ku lasiko tawọn agbebọn fẹẹ ji oyinbo gbe l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo O kere tan, awọn afurasi Fulani mẹrin lọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti…

 Musulumi aarẹ ati igbakeji: Agbẹjọro wọ APC, Tinubu lọ sile-ẹjọ

Monisọla Saka Agbẹjọro kan to filu Abuja ṣe ibugbe, Osigwe Momoh, ti wọ ẹgbẹ oṣelu APC…

Wọn ti sinku Asẹyin ti ilu Isẹyin to waja

Ọlawale Ajao, Ibadan Wọn ti sinku Asẹyin tilẹ Iṣẹyin, Ọba Abdul Ganiyu, Adekunle Salawudeen (Ajinẹsẹ Kin-in-ni),…