O ma ṣe o! Ọmọ alaga kansu Ogbomọṣọ padanu ẹmi ẹ sinu ijamba ọkọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Inu ọfọ nidile Oritokẹ, alaga ijọba ibilẹ Onidagbasoke Aarin-Gbungbun Ogbomọṣọ wa bayii, pẹlu…

Ajọ eleto idibo ti fun Ademọla Adeleke niwee-ẹri ‘mo yege’

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ajọ eleto idibo ilẹ wa ti fun gomina tuntun ti wọn ṣẹṣẹ dibo…

Awọn agbebọn ji Babs oniburẹdi gbe n’Ifẹwara, miliọnu marun-un ni wọn n beere

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkunrin oniburẹdi kan to n gbe niluu Ifẹwara, nipinlẹ Ọṣun, Sikiru Adebisi, la…

Portable ti fẹnu kọ o, ọga ọlọpaa patapata ti paṣẹ ki wọn mu un

Faith Adebọla Ko jọ pe wọn ru ẹbọ olubọbọ tiribọ, baba ẹnu, fun gbajugbaja onkọrin taka-sufee…

Awọn aṣofin yọ igbakeji gomina Ọyọ, wọn fi Bayọ Lawal rọpo rẹ

Monisọla Saka Ni Mọnde, ọjọ Aje, ọsẹ yii, ni awọn aṣofin ipinlẹ Ọyọ yọ igbakeji gomina…

Adeleke bu sẹkun gbaragada nigba ti ajọ eleto idibo kede re bii gomina Ọṣun tuntun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Omije ayọ lo gba oju gomina ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan nipinlẹ Ọṣun,…

Eyi ni awọn ijọba ibilẹ ti PDP, APC ti bori

Florence Babaṣọla Ijọba ibilẹ mẹtadinlogun, ninu ọgbọn ni Ademọla Adeleke to ṣẹṣẹ jawe olubori ninu eto…

Eyi ni orukọ awọn ijọba ibilẹ ti PDP, APC ti bori

Florence Babaṣọla Ijọba ibilẹ mẹtadinlogun, ninu ọgbọn ni Ademọla Adeleke to ṣẹṣẹ jawe olubori ninu eto…

Esi ibo gomina: Mọlẹbi Adeleke, ẹgbẹ PDP n dawọọ idunnu l’Ọṣun

Florence Babaṣọla Beeyan ba gẹṣin ninu awọn mọlẹbi ẹni ti ajọ eleto idibo ṣẹṣẹ kede gẹgẹ…

Ademọla Adeleke jawe olubori nibi idibo Ọṣun

Florence Babaṣọla Ademọla Adeleke to dije lorukọ ẹgbẹ oṣelu PDP nipinlẹ Ọṣun lo jawe olubori nibi…

Iṣẹ abẹ ti wọn ṣe fun Ọṣinbajo kẹsẹ jari, yoo jade lọsibitu laipẹ

Orẹoluwa Adedeji Iroyin to tẹ ALAROYE lọwọ ni pe wọn ti ṣiṣẹ abẹ ẹsẹ ti wọn…