Dapọ Abiọdun gbe abajade ikọlu awọn Fulani ati agbẹ ipinlẹ Ogun lọ sọdọ Buhari

Gomina ipinlẹ Ogun, Ọmọọba Dapọ Abiọdun, ree pẹlu Aarẹ Muhammadu Buhari, lasiko ti Gomina gbe akojọpọ ati abajade ikọlu to waye nipinlẹ Ogun lọ fun un l’Abuja.

Ọjọ Ẹti, Furaidee,  ọjọ kọkandinlogun, oṣu keji yii, ni gomina gbe abajade naa lọ fun Aarẹ Buhari.

Leave a Reply