Esi awọn ifẹsẹwọnsẹ to pari Premier League ilẹ England fun saa 2019/20

Oluyinka Soyemi

Lonii ni awọn ifẹsẹwọnsẹ to gbẹyin saa 2019/20 ninu idije Premier League ilẹ England waye.

Liverpool, Manchester City, Manchester United ati Chelsea lo wa ni ipo kin-in-ni si ikẹrin, awọn ni yoo si lanfaani lati kopa ninu idije Champions League to n bọ lọna.

Bournemouth, Watford ati Norwich City lo wa ni ipo kẹta to gbẹyin, wọn si ti ja kuro ni Premier League bayii.

Esi awọn ifẹsẹwọnsẹ ti oni niyi:

Arsenal 3  Watford 2

Burnley 1  Brighton 2

Chelsea 2  Wolves 0

Crystal Palace 1  Tottenham 1

Everton 1  Bournemouth 3

Leicester 0  Man U 2

Man City 5  Norwich 0

Newcastle 1  Liverpool 3

Southampton 3  Sheffield 1

West Ham 1  Aston Villa 1

Leave a Reply