Fayẹmi, Boroface ati Dimeji Bankọle naa ti juwọ silẹ fun Aṣiwaju Bọla Tinubu

Sẹnetọ to n ṣoju ipinlẹ Ondo, Gomina ipinlẹ Ekiti, Dokita Kayọde Fayẹmi, Gomina ipinlẹ Jigawa, ati olori ileegbimọ aṣoju-ṣofin tẹlẹ, Dimeji Bankọle, lawọn naa ti juwọ silẹ, wọn si rọ awọn aṣoju wọn lati dibo wọn fun Aṣiwaju Bọla Tinubu.

Leave a Reply