Fidio: Aṣiri nla! Eleyii le o, ẹ fura o

Ẹyin ti ẹ n fi gbogbo awọn nnkan nipa akaunti yin sori foonu, afi kẹ ẹ ṣọra ṣe o, nitori ti foonu naa ba ti sọnù, o ṣeé se kẹ ẹ padanu gbogbo owo tẹ ẹ ba ni ni banki.
Ẹnìkan lo fi Fodio yii ránṣẹ́ si ALAROYE, nibi ti ọmọkùnrin kan tawọn agbofinro mu ṣe n ka bòrọ̀bọ̀rọ̀ lori bi wọn ṣe maa n lo foonu ti wọn ba ji lati wọ gbogbo owo to ba wa lakaunti ẹni to ni in.
Bẹẹ lo ni awọn le fi akaunti ẹni tawọn ba ji foonu rẹ tawo paapaa.

 

Leave a Reply